album cover
Buga Won
album cover
Buga Won fue lanzado el 15 de agosto de 2025 por Quantum MST como parte del álbum Buga Won - Single
15 de agosto de 2025
Sello discográficoQuantum MST
IdiomaEnglish
BPM114
Melodía
Nivel de sonidos acústicos
Valence
Capacidad para bailar
Energía

Letra

[Verse 1]
Mi o fọ fun yin, hmm
Ọlọrun nikan ni mo fọ fun jọ
Ọmọ ẹru jọba
Ọlọrun sọ pe emi lo fẹ fun, jọ
One, you no fit run my race
Two, no formula for grace
So know your place
No be sey I holy pass them but na god dey judge my case
[PreChorus]
Wọn ni fi ẹlomi ṣe mi, ma ṣe bi mo ṣe mọ
Oluwa dabo rẹ bo mi bi mo ṣe n lọ bi mo ṣe n bọ
Ma fohun mi yin ọ
Ma jẹ ko ha bi mo ṣe n kọ
Jọ, ṣebi iwọ lo ni ki n ma ṣe lọ
[Chorus]
Ma buga wọn, buga wọn lọ
Mi o tẹle wọn, mi o tẹle wọn lọ o, wọn lo o
Ọrọ aye mi ko ma ye mi gan-an, mi gan-an o
Ko ye mi rara o ye Ọlọrun, ye Ọlọrun
[Chorus]
Ma buga wọn, buga wọn lọ
Mi o tẹle wọn, mi o tẹle wọn lọ o, wọn lo o
Ọrọ aye mi ko ma ye mi gan-an, mi gan-an o
Ko ye mi rara o ye Ọlọrun, ye Ọlọrun
[Verse 2]
Mi o le ba wọn lọ coz mi o ba wọn wa
Upon mo n jaye mi lọ ki lẹ fẹ ma ba mi fa
Ẹni ba ma ba wa lọrọ yii o, a lọ far
Onto, ẹpọn o lejika
Ṣo ye?
Wọn o ni fi ẹlomi ṣe mi, ma ṣe bi mo ṣe mọ
Ṣebi na the one wey I know I go do, I no go do pass myself
Ole lo bọmọ jẹ, jama jama you go tidy yourself
Idan mi, hustle pawo make you no go sleep on yourself
[Verse 3]
I'm talented, I'm stupendous
I dey calcu I dey watch before I try to cross
No dey don't play with my anointing boss
Holy Spirit fall on me like say na pentecost
Dem say we arrogant dem dey try kill us
And as dem no see us kill dem dey envy us, no
I paid my dues I paid the cost
If you no believe go fight Jesus
[PreChorus]
Wọn ni fi ẹlomi ṣe mi, ma ṣe bi mo ṣe mọ
Oluwa dabo rẹ bo mi bi mo ṣe n lọ bi mo ṣe n bọ
Ma fohun mi yin ọ
Ma jẹ ko ha bi mo ṣe n kọ
Jọ, ṣebi iwọ lo ni ki n ma ṣe lọ
[Chorus]
Ma buga wọn, buga wọn lọ
Mi o tẹle wọn, mi o tẹle wọn lọ o, wọn lọ o
Ọrọ aye mi ko ma ye mi gan-an, mi gan-an o
Ko ye mi rara o ye Ọlọrun, ye Ọlọrun
[Chorus]
Ma buga wọn, buga wọn lọ
Mi o tẹle wọn, mi o tẹle wọn lọ o, wọn lọ o
Ọrọ aye mi ko ma ye mi gan-an, mi gan-an o
Ko ye mi rara o ye Ọlọrun, ye Ọlọrun
Written by: Daniel Bode Elijah
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...