Paroles

Ti aiye ba ti nyi, Ishola, ka mia bawo yii Opon Apala ti sun fainally, Oti kuro ni ti atijo Ishola Tunde Musiliu Ayinla mi Josuha Oo E jowo ebi mi daa lu bo Le alujo ni kiya mosa Ti aiye ba ti nyi, Ishola, ka ma bawo yii Opon Apala ti sun fainally, Oti kuro ni ti atijo Ishola Tunde Musiliu, Ayinla mi Josuha Oo E jowo ebi mi daa lu bo Le alujo ni kiya mosa Oju wa niyo shey, baluwe to ni un o'dodo unla oo Ishola Tunde Musiliu, Sha ma wo won niran Eyin l'omo adiye un to'ya ee, Ko si ewu fun wa Raraaaaaaaa Enu won ni yio pawon, Babatunde oda'miloju Eiye orofo t'obi mo meji, ti'onile oun ti kun shosho Asiko tito ta-ao so'fun pe asiwaju yin'laje Koni buuru fun Ori, ki' ade fila si'orikun ese Koni buuru fun Ori, ki'ade fila si'orikun ese Enu won mefa, Enu-u won meje Awa o'ba elenu meji se ere mo-ooooo Ba'Ala ni soro, Oro a sorare to-oba unpe Won si mi-a tun le lee'enu debe, Musiliu Egungunjobi Aa'dijo maa ko-orin Apala, Tunde iyen odita Igberaga un'sewon Babatunde Haruna mo-un tenumo Loju-ojumo Ooo Awon da? Won-oo da dan mo Awon da? Won-oo ni logo Awon da? Won-oo da dan mo Awon da? Won-oo ni logo Didan yio ma dan, Ise Oluwa, eyin ema tuu wo Didan yio ma dan, Ise Oluwa, eyin ema tuu wo Yungba yungba, l'aiye wa yio ma dun Oooo
Writer(s): Musiliu Haruna Ishola Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out