Titres les plus populaires de King Sunny Ade
Titres similaires
Crédits
INTERPRÉTATION
King Sunny Ade
Interprète
COMPOSITION ET PAROLES
King Sunny Ade
Paroles/Composition
Paroles
Gbogbo awon ayanfe e lo se logo
Oluwa lo pe mi lo yan mi wa, gbogbo awon ayanfe e lo se logo
Oluwa lo pe mi lo yan mi wa se, gbogbo awon ayanfe e lo se logo
Oluwa lo pe mi lo yan mi wa, gbogbo awon ayanfe e lo se logo
Kita kita ko ran, giri giri ko ran o
Kita kita o ran o, giri giri ko ran o
Ori lo pin ola koni, ori lon pin ola koni
Eda mi pin temi komi, maa je n si won w'aye
Ori mi maa je n si won w'aye l'aye lasan lasan
Eda mi ma je n se akobata fun egbe mi
Tori kita kita o ran o, giri giri ko ran o
Kita kita o ran la, giri giri o ran o
Ori lo pin ola koni, ori lon pin ola koni
Eda mi pin temi komi, maa je n si won w'aye
Emi ti gbo ohun Oluwa ti o wipe
Bawa arakunrin o, dide ni ogba ajara Oluwa e ko si ma korin
Bawa arakunrin o, dide ni ogba ajara Oluwa e ko si ma korin
Aye le ma sata
Aba, Let them say
Writer(s): King Sunny Ade
Lyrics powered by www.musixmatch.com