Clip vidéo

Apparaît dans

Crédits

INTERPRÉTATION
Asake
Asake
Interprète
COMPOSITION ET PAROLES
Ahmed Olalade Asake
Ahmed Olalade Asake
Paroles/Composition
PRODUCTION ET INGÉNIERIE
Magicsticks
Magicsticks
Production

Paroles

(Tune in to the king of sounds and blues) Ọlọlade mi, Àṣàkẹ (Hey, help me, help me, help me) (Help me, help me, help me, help me, help me) (He dey carry me dey go where I no know) Padi mi, hustle lọ Ṣ'o di gba ti ń bá ni, "Ko buckle up?" Alaye mi, saare tẹ button lọ Gbogbo nkan kọ l'oma fi ń jọgọ, jọọ, jọọ Ká lọ ṣe shoppin', jọọ I no dey send, I dey chop my life Hundred percent, we dey gbadun lọ Àwọn ti o fẹ wa, k'oma struggle lọ, lọ, lọ The money long 'cause I don fa'ṣẹ Na everybody want to tear my shirt I just blow but, ọmọ, I know my set Before them use me, I go use my sense, my sense Ọmọ ọba to n pàṣẹ Anita-'nita-'nita-'nita, go down, sẹ Ọmọ dudu, ọmọ pupa, emi l'oma fẹ Range Rover méjì, elo l'oma jẹ, jẹ, jẹ? Asalamalekun I get many-many disciple Mo ta'ka òṣì dànù Olúwa, shower me your blessings times two (O dẹ jọwọ-jọwọ) O dẹ jọwọ (jọwọ), ko dahun (ko dahun) In every situation, make I no lose (make I no lose) Emi o ṣákọ mọ, Ọlọhun Jẹ k'àwọn padi ma biza, thank you (ahh) Emiliano, rọra (rọra) Ko ṣá ma rọra (ko ṣá ma rọra) Ìwọ nikan ni corner (corner) Mo da mọ, Tọla 'Cause you dey para pass your mother (Bara') Baraka De Sallah Ilefo chameleon Mo ti gbe wọn de'bẹ The money long 'cause I don fa'ṣẹ Na everybody want to tear my shirt I just blow but, ọmọ, I know my set Before them use me, I go use my sense, my sense Ọmọ ọba to ń pàṣẹ Anita-'nita-'nita-'nita, go down, sẹ Ọmọ dudu, ọmọ pupa, emi l'oma fẹ Range Rover méjì, elo l'oma jẹ, jẹ, jẹ? Asalamalekun I get many-many disciple Mo ta'ka òṣì dànù Olúwa, shower me your blessings times two (O dẹ jọwọ-jọwọ) O dẹ jọwọ-jọwọ, ko dahun (ko dahun) In every situation, make I no lose Emi o ṣákọ mọ, Ọlọhun Jẹ k'àwọn padi ma biza, thank you (ahh)
Writer(s): Temitayo Kareem, Ololade Ahmed Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out