Clip vidéo
Clip vidéo
Crédits
INTERPRÉTATION
Poco Lee
Chant
Shoday
Chant
Rahman Jago
Chant
COMPOSITION ET PAROLES
Poco Lee
Paroles
Shoday
Paroles
Rahman Jago
Paroles
Producer X
Composition
PRODUCTION ET INGÉNIERIE
Producer X
Production
Paroles
[Intro]
Heyyy, Jago
Heyyy, Jago
Heyyy, Jago
Heyyy, Jago
[Verse 1]
He dey press money before
That one na old taker
Me seff go press for sure
I be the new taker ahh ahh
Wọn ti gbezome
Old taker ti gbezome
Ma lọ gbezome
Ọmọ aunty mi no gbezome
[Chorus]
Hey Jago
What's popping, Jago?
High fashion, Jago
Figo o ma ki n ṣe wazo oh
Hey, Jago
Emi eeyan, Jago
Shoday eeyan Paso
Lambo o ma ki n ṣe wazo oh
[Verse 2]
Hey, Jago
Gbogbo aṣọ lo ni bata
CEO highfashion tia
Ọmọ Tiamiyu gan-an gan-an
Wọn damọ l'Oke-Koto
Atobaje wọ Morikaz
Oju-Irin, Pencinema
Aja 1, aja 2
Gbe wa sare wọ Switzerland
Wọn damọ l'America
Highfashion wọ Canada
O yeruku, Jago is loud
[Verse 3]
Ti n bari fifty dollar ma ganu sibẹ
No money is ever enough
Ta, ta, ta bi Dangote
Kowo mi kun soke
I left home to feed home
Mo jade tan wọn se jollof
Go hard or go home
Ọmọ iya mi mo sa lọle, ehh
[Chorus]
Hey Jago
What's popping, Jago?
High fashion, Jago
Figo o ma ki n ṣe wazo oh
Hey, Jago
Emi eeyan, Jago
Shoday eeyan Paso
Lambo o ma ki n ṣe wazo oh
[Verse 4]
Hey, Jago
Gbogbo aṣọ lo ni bata
CEO highfashion tia
Ọmọ Tiamiyu gan-an gan-an
Wọn damọ l'Oke-Koto
Atobaje wọ Morikaz
Highfashion wọ Canada
O yeruku, Jago is loud
[Outro]
Heyyy, Jago
Written by: Poco Lee, Rahman Jago, Shoday

