Crédits
INTERPRÉTATION
Tolibian
Chant
ODUMODUBLVCK
Interprète
Boj
Interprète
COMPOSITION ET PAROLES
Tochukwu Ojogwu
Paroles/Composition
Abubakar Ottan Abdulmutolib
Paroles/Composition
Bolaji Odojukan
Paroles/Composition
PRODUCTION ET INGÉNIERIE
Agu Uchechukwu James ‘Ucee’
Production
Farouk Omaki ‘Cross’
Production
Great Udhe ‘Greamar’
Production
Paroles
[Chorus]
Saari, saari ti to Musulumi ẹ dide n'lẹ kẹ jẹun o
Ehn, lọsan Ramadan
Oju mi ti ri lọsan Ramadan
B'ọn gbounjẹ wa, mi o ni le jẹun
B'ọn gbomi wa, mi o ni le mu o
Agba to lomi 'nu o ki n pariwo mo ti n gbawẹ
La la la la la la uwe
[Verse 1]
Black sheep forever, black sheep for life
Izgaaju 'til we kpeme, Antiworld gangsters, GE records, you get me? ODUMODUBLVCK
Kala
Musa serve me masa with suya
Iftar na where we my **** dey gather
If you think I'm fapping meat, you are right hoarding meat
For Jago house after everything him praying tarawih
For ABJ city we dey jolly
Ramadan Kareem (O pọ)
They will give me anything I want
Asun for sahoor
Alfa gimme more
[Verse 2]
Lalẹ Ramadan (Ehn)
Ṣa ma pade lọdọ alhaja?
Lalẹ Ramadan (Ehn)
Ibẹ la ti n ma ṣe iftar
Lalẹ Ramadan (Eyy)
Assalam alaikum, wa alaikum assalam
Ẹ dide, ẹ dide, ẹ dide 'lẹ
[Chorus]
Saari ti to Musulumi ẹ dide n'lẹ kẹ jẹun o
Ehn, lọsan Ramadan
Oju mi ti ri lọsan Ramadan
B'ọn gbounjẹ wa mi o ni le jẹun
B'ọn gbomi wa mi o ni le mu o
Agba to lomi 'nu o ki n pariwo mo ti n gbawẹ
La la la la la la uwe
[Verse 3]
Ẹ ye fa bakky lọsan Ramadan
Ẹ ye gboloṣo lọsan Ramadan
Ẹ ma ṣe ṣaṣe ninu Ramadan
O ṣi tun wẹṣẹ ninu Ramadan
[Outro]
Yeah, yeah, yeah
Yeah, yeah, yeah
Written by: Abubakar Abdulmutolib Ottan p/k/a Tolibian, Abubakar Ottan Abdulmutolib, Bolaji Odojukan P/k/a Boj, Tochukwu Gbubemi Ojogwu P/k/a ODUMODUBLVCK, Tochukwu Ojogwu

