album cover
Dide
album cover
Dide 24 जुलाई 2026 को DEJER / UNCLE SHABA द्वारा एल्बम Dide - Single के एक भाग के रूप में रिलीज़ किया गया था
एल्बमDide - Single
24 जुलाई 2026
लेबलDEJER / UNCLE SHABA
BPM125
मधुरता
ध्वनिकता
वेलेंस
डांस करने की क्षमता
ऊर्जा

म्यूज़िक वीडियो

म्यूज़िक वीडियो

गाने

[Intro]
Dide irawọ mi
Dide, dide, dide
Dide, dide, dide, dide
[Chorus]
Dide irawọ mi
Fọ oju ẹ ma sunkun mọ
Dide irawọ mi
Fọ oju rẹ ma sun
Dide irawọ mi
Lailai, lailai, lailai
Dide irawọ mi
Lailai, lailai
Fọ oju ẹ ma sunkun mọ
Fọ oju ẹ ma sun
Lailai, lailai, lailai
Lailai, lailai
[Verse 1]
Jẹ ki omije mi parẹ
Mo ran ti igba yẹn
Ta n fẹ ba mi ṣeré
Ẹjẹ mi ṣàn lọwọ ati oju
Wọn boju wọn fẹ ri iworan mi
Jọwọ dakun ẹ gba mi
[Chorus]
Lailai, lailai
Lailai, lailai
Dide irawọ mi
Fọ oju ẹ ma sunkun mọ
Dide irawọ mi
Fọ oju ẹ ma sun
Dide irawọ mi
Lailai, lailai, lailai
Dide irawọ mi
Lailai, lailai
[Outro]
Shaba
Lailai, lailai
Written by: Abibat Busola Ogunlana, Otaniyen-Uwa Daniel
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...