Lirik

Òní wàràpá tí rọlú mágún (kasa!) Kokanmi, kokanmi Qdot lórúkọ mí (kokanmi, kokanmi) Mo mọ pé mo mí lẹ́ ṣé ń f'ọbo lọmi Mí o l'órí lo gùn pé ìbon ó lé rán mí Bíbélì mọ ní pẹ'lú Qurani Pẹ'lú kíní báàmí tó ń dùn woro-woro Ẹní f'ojú dí iná, iná à jo Ìyá Ìbàdàn, óyà, gb'àgbo lè 'ná Èpò ọ'gẹ'dẹ' kò lé yó mí Máapẹ bí Aláàfin Ọ'yọ' ní We're' ní wọn mó má lé wọn s'Aro Má gbé wọn lọ bí 'dò-dò Ìyá Aláró Ẹ fún mí hammer, kín fọ wọn lórí ká Àwọn we're', àwọn motherfucker Ẹ ro dádá k'ẹto b'Èṣù lówé Ẹ sọ fún Ṣígidi, kò má r'odò lọ wẹ Kílóńjẹ' kò s'ewé, kò s'egbò nínú àyé? K'Ọlọrun májẹ à rí'já àyé ní Shi-o kelẹbẹ (kokanmi) Wọn ní pé, "Picker die" (kokanmi) Pé client ó sọrọ mọ (kokanmi) Pé ìyàwó yín ń ṣé oloṣo (kokanmi) Ó sún yàrá landlord (kokanmi) Wọn fẹ mo'dí abájọ (kokanmi) Taní bàbá alájọ? (Kokanmi) Ẹ re ilé bàbálawo (kokanmi) Ẹbọ yìn má fọ m'awo (kokanmi) Wọni pé Yahoo ní (kokanmi) Wọni pé à ṣ'ogun owó (kokanmi) Òní wàràpá rọlú mágùn (kokanmi) Pé Lagbaja b'ójú k'orin (kokanmi) Ẹní òyìnbó ó dùn lẹ'nu mí (kokanmi) But local mí ń ja'wó (kokanmi) Òkè Kilimanjaro sọpé Olumo ó gá Àgbọ' t'ajá, àgbọ' t'ẹran Èwo ní t'àgùntàn lórí àga Wọn ní mọ local, mo ń pa'wó lọ Ọmọ Folashade, mo tí gba'dé lọ Òyìnbó lé má dùn lẹ'nu mí Èyí tí ń bá sọ, Wole Soyinka l'aba yìn tu Ẹ wá wo èlékó tó yàn'dì s'oní moi-moi Òní bùgan bínú ẹlẹ́wà àgóyìn I don't care if you like or not Ẹní ṣíṣẹ ló má pa'wó Kòkòrò tó ń jó leba ònà ní, onílù re ń bẹ nínú igbó Mó tí gòkè, mó tí ṣé lọ k'afara tó já Mó japa, k'òyìnbó tó já Ọmọdé àná tí wá d'àgbà Qdot, ọmọ imalẹ afeleja Ẹ ro dádá k'ẹto b'Èṣù lowe Ẹ sọ fún Ṣígidi, kò má r'odò lọ wẹ Kílóńjẹ' kò s'ewé, kò s'egbò nínú àyé? K'Ọlọrun májẹ à rí'já àyé ní Shi-o kelẹbẹ (kokanmi) Wọn ní pé, "Picker die" (kokanmi) Pé client ó sọrọ mọ (kokanmi) Pé ìyàwó yín ń ṣé oloṣo (kokanmi) Ó sún yàrá landlord (kokanmi) Wọn fẹ mo'dí abájọ (kokanmi) Taní bàbá alájọ? (Kokanmi) Ẹ re ilé bàbálawo (kokanmi) Ẹbọ yìn má fọ m'awo (kokanmi) Wọni pé Yahoo ní (kokanmi) Wọni pé à ṣ'ogun owó (kokanmi) Òní wàràpá rọlú mágùn (kokanmi) Pé Lagbaja b'ójú k'orin (kokanmi) Ẹní òyìnbó ó dùn lẹ'nu mí (kokanmi) But local mí ń ja'wó (kokanmi) Jirafa jalika ra fali eli Malaika mí Orimolade Ẹní f'ojú dí iná, iná à jo Ìyá Ìbàdàn, óyà, gb'àgbo lè 'ná Èpò ọ'gẹ'dẹ' kò lé yó mí Máapẹ bí Aláàfin Ọ'yọ' ní K Sir Sosse King of Marley Musa Felix for Garuba Femi Jaguar nílùú London Mo mọ Baddy Oosha Lanre Typical Milli ọmọ Salawe Mo mọ Femi Chill Music Mo mọ Billique (mo mọ Billi') Mo mọ Doctor Brown Mo mọ Arowolo, Arowolo tí ń tá motor Mo mọ Bottles, IBD Dende Aláṣẹ Nikas Teni Level Motí mọ Water Mo mọ Owo Mabo Bunmi simple casher Mo mọ Unique Motors Mo mọ Climax Mo mọ Pasuma Wonder, ọmọ ìyàwó Anọbi l'Omole Xsmile (Yeah, who's here?) Quick as sure boys
Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out