Lirik

Olúwa a ma ń ríṣẹ yín oo Olúwa a ma ń rọwọ yìn oo Àwọn to tí gan wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ Olúwa a ma ń rọwọ yín oo Olúwa a ma ń ríṣẹ yìn oo Àwọn to tí yọ wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ O máa ma ṣé elédùmarè O máa ma ṣé o alátìlẹyìn Àní bí ki ba ṣé ìfẹ' rẹ oo oo oo kìíní báma wí O máa ma ṣé o elédùmarè O máa dúpẹ' dúpẹ' dúpẹ' alátìlẹyìn Àní bí ki ba ṣé ìfẹ' rẹ oo oo oo kìíní báma wí Olúwa a ma ń ríṣẹ yín oo Olúwa a ma ń rọwọ yìn oo Àwọn to tí gan wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ Olúwa a ma ń ríṣẹ yín oo Olúwa a ma ń rọwọ yìn oo Àwọn to tí yọ wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ Bí kò bá ṣe ìwọ Jésù Tó dúró tì mí lẹ'yìn Ènìyàn dúró láti bámijà wọn fẹ ṣẹlẹ̀yà mí Bí kò bá ṣe ìwọ Jésù Tó dúró tì mí lẹ'yìn Ènìyàn dúró láti bámijà wọn fẹ ṣẹlẹ̀yà mí Eeee eeee eeeeeee Olúwa a ma ń ríṣẹ yín oo Olúwa a ma ń rọwọ yìn oo Àwọn to tí gàn wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ Olúwa a ma ń ríṣẹ yín oo Olúwa a ma ń rọwọ yìn oo Àwọn to tí yọ wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ Gbogbo àwọn tátí rán lọ'wọ' tán ṣe bí Ọlọ'run kò wá tán bí Àwọn to tí gàn wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ Gbogbo àwọn tọ' ti rò wá pín tán ṣe bi Ọlọ'run kò wá tán bí Àwọn to tí yọ wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ Eẹẹẹẹẹ Ibi ẹ fojú sí ọ'nà o gbà bẹ Mọ tí lọ mọ' yín lọ'wọ' oooo Àwọn to tí gàn wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ Àwọn to tí gàn wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ Àwọn to tí yọ wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ Àwọn to tí gàn wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ Àwọn to tí gàn wa tu ń wa ń fọlá wa tọrọ Ẹhn ẹhn ẹhnẹhn
Writer(s): Dammy Bee Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out