Testi

Mo nlọ s'Ake, mo fẹ' lọ rọ'jọ'gbọ'n o Mo nlo s'Abeokuta, mo fe lọ ri Omo Soyínka Osoyinka Osoyinka Osoyinka Be lọ s'Owu Be ba r'Aremu o Be ba ri Baba Iyabo, ẹ ba mi ki Ẹbọra Owu Ẹbọra Owu oo Ẹbọra Owu, eeh Ẹbọra Owu oo Be lọ s'Abeokuta, ìlo Olúmọ Bẹ ba r'Alake, ẹ ba mi ki
Writer(s): Olawale Ibrahim Ashimi Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out