Testi

Lord, I've come to seek Your face Let Your grace and Your mercy come upon me, Lord Oh Lord, I call upon Your name Let the rain of Your mercy pour upon me, Lord Oluwa, mo wa sibi ite Je ki oore ofe ati aanu Re, Oluwa Ko ba le mi lori Oluwa, mo ke p'Oruko Re Je ki ojo aanu Re o, Baba Ko ro s'ori iseda mi Baba ooooo, eyi l'ebe o Baba Alaanu, Olugbebe, gbo ebe mi Oluwa o (Baba ooooo, eyi l'ebe o) Aye mi ko bu ola fun O ni mo n beere (Baba ooooo, eyi l'ebe o) Ona mi to wo, Ko di tito ninu ife Re Oluwa o, Eyi ni ebe mi o Gba mi lowo asise, Oluwa o (Baba ooooo, Eyi l'ebe o) Gba mi lowo ogun t'apa obi mi o ka, Gba mi lowo ogun irandiran, Oluwa gba mi oo Baba, Iwo ni mo gbeke mi le o, Eni to ni emi mi Oluwa too ba to mu awon afoju san, (Baba ooooo, Eyi l'ebe o) Oba to ji oku omo Jairu dide, Oku Lasaru, Ojo merin, o ti n ra, o ti n run, Iwo lo ji i dide o, Oluwa saanu mi Jesu, omo Dafidi, gbo adua mi, Oluwa (Baba ooooo, eyi l'ebe o) Baba oooo, Oore ofe Re ni mo beere, aye o see gbe laisi oore ofe Re, Oluwa o Mo fi oore ofe Re ra aye gbe, Oluwa (Baba ooooo, eyi l'ebe o) Atupa imo mi ko ma se ku lailai (Baba ooooo, Eyi l'ebe o) Iwo ni opo fitila to n tan fun emi mi Oluwa ooo Oro Re wipe bi mo beere, ma a ri gba, Mo n beere ki n ri gba (Baba ooooo, eyi l'ebe o) Bi mo ba kan 'lekun, Ilekun a si, ilekun ko si, a si ti ko wipe, Bi mo ba wa kiri, ma a ri, Mo n wa kiri, ki n ri o, ki n ni ere to po, Oluwa o Baba Alaanu ooo (Baba ooooo, Eyi l'ebe o) Ohun gbogbo to wa ninu iseda n gbimo aanu Si ayanmo mi, won n sise iranwo lori ayanmo mi, Oluwa o Ilekun si le, ilekun aanu si le, Oluwa (Baba ooooo, Eyi l'ebe o) Aanu ro sori mi, o ro sori mi bee, Olugbebe gbo ebe mi o Oh Lord I've come to seek Your face Let Your grace and Your mercy come upon me, Lord Oh Lord, I call upon Your name Let the rain of Your mercy pour upon me, Lord Oluwa, mo wa sibi ite Je ki aanu ati oore ofe Re Ko ba le mi lori Oluwa, mo ke p'Oruko Re Je ki ojo aanu Re Ko ro s'ori iseda mi Baba ooooo, eyi l'ebe o Baba ooooo, eyi l'ebe o
Writer(s): Sola Allyson Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out