album cover
Mafo
383.842
World
Mafo è stato pubblicato il 1 gennaio 2019 da MOVES Recordings come parte dell'album Lol (Lord of Lamba) - EP
album cover
Più popolari
Ultimi 7 giorni
00:00 - 00:05
Mafo è stata scoperta più frequentemente nei primi secondi di la canzone durante la settimana passata
00:00
00:10
00:20
00:30
00:35
01:00
01:20
01:30
01:40
01:45
02:10
02:20
02:35
02:40
02:50
03:00
03:05
03:20
03:25
00:00
03:34

Testi

[Intro]
Jigi
It's Young Jonn, wicked producer
[Verse 1]
Eko dun ma bọ n'le
To ba ti lowo lapo
Aṣabi to n ṣa dollar
Awọn padi mi t'ọn ṣe wire
Eko dun ju bayii lọ
Awọn ara ibi lo mu ọmọ ọpẹ salọ
Owo wa l'Eko
Awọn kan wa okay
Ma lọ fọ bi awo
Awa o le salọ fun wọn
T'ọn ba de, a ma ki wọn kaabọ
Awa la l'Eko iwọ ma fọ
Ma fọ!
[Verse 2]
Inside life
Oriṣiriṣi nnkan lo n ṣẹlẹ
Lagbo Young Jonn, oriṣiriṣi idi lo n bẹ n bẹ
Kuo n'bẹ
[PreChorus]
Quarter pass
O ṣi fẹ high
After one, original Tramadol Extra
Quarter pass
O ṣi fẹ high
After one, original Tramadol Extra
[Chorus]
Gbess ma fọ
Ah ma fọ
Ko si eeyan be jọwọ ma fọ
Hmm, ma fọ
Gbess ma fọ
Ah ma fọ
Oje l'ọn lo jọ, iwọ ma fọ
Hmm, ma fọ
[Verse 3]
Mo fẹ rowo na
Mo fẹ Bisola
K'ọla yiwọla, ki n tun ji, ki n tun jibọla
[Verse 4]
O n pẹ k'ọn to na Bọda Ade
Bọda Ade ti o n sanwo aye
Wọn wa catch e ninu aye
Wọn wa catch, won wa fuck ẹ up ninu aye
[Verse 5]
Eh, ẹ wa ṣe mo guilty ni?
Mo n smart, mo n pawo ni temi
Ṣo mọ iye time ti o ju n ti mi
Ti mo le tọrọ owo lọwọ Rotimi
[Verse 6]
Now everything's changed
I sent them shock, I don't need a change
Am I a Yahoo Boy no evidence?
Emi eeyan Rahman Jago, Bureau De Change
Kuro n'bẹ
[Chorus]
Gbess ma fọ
Ah ma fọ
Ko si eyan be jọwọ ma fọ
Hum ma fọ
Gbess ma fọ
Ah ma fọ
O je lo n lo jọ, iwọ ma fọ
Hum ma fọ
[Bridge]
Young Jonn, say no more
Ko sọrọ pe mi o
+ 4-4-9-4-0-4 but iwọ ma fọ
[Verse 7]
O ba ni ko bajẹ, ma fọ
Ọmọ iya mi, mo wa pẹlu ẹ, ma fọ
Stay happy and ṣe jẹjẹ, ma fọ
You know that I dey with you, ma fọ
O ba ni ko bajẹ, ma fọ
Ọmọ iya mi, mo wa pẹlu ẹ, ma fọ
Stay happy and ṣe jẹjẹ, ma fọ
You know that I dey with you, ma fọ
[PreChorus]
Quarter pass
O ṣi fẹ high
After one, original Tramadol Extra
Quarter pass
O ṣi fẹ high
After one, original Tramadol Extra
[Chorus]
Gbess ma fọ
Ah ma fọ
Ko si eeyan be jọwọ ma fọ
Hmm, ma fọ
Gbess ma fọ
Ah ma fọ
Oje l'ọn lo jọ, iwọ ma fọ
Hmm, ma fọ
[Verse 8]
O ba ni ko bajẹ, ma fọ
Ọmọ iya mi, mo wa pẹlu ẹ, ma fọ
Stay happy and ṣe jẹjẹ, ma fọ
You know that I dey with you, ma fọ
[Outro]
Ma fọ
Ma fọ
Ma fọ
Ma fọ
Ma fọ
Ma lọ fọ bi awo
Written by: Azeez Fashola, Chisom Ezeh, Udomboso Jonn Savious
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...