Crediti

PERFORMING ARTISTS
Benjamin Paul
Benjamin Paul
Claves
Olanipekun Sunday - Talking Drummer
Olanipekun Sunday - Talking Drummer
Drums
Opasho Femi Pablo
Opasho Femi Pablo
Drums
Shadeko Juwon Gideon
Shadeko Juwon Gideon
Background Vocals
Abik Sarah
Abik Sarah
Background Vocals
Michael Samson -Mksongz
Michael Samson -Mksongz
Background Vocals
Onaadepo Olusola
Onaadepo Olusola
Background Vocals
Adeyemi Samuel - Omele Bata
Adeyemi Samuel - Omele Bata
Drums
Omoyayi Deborah
Omoyayi Deborah
Background Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Adebayo Oladipupo Temitope
Adebayo Oladipupo Temitope
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Adebayo Omogbolahan (G-bass)
Adebayo Omogbolahan (G-bass)
Mixing Engineer
RESOUND STUDIO
RESOUND STUDIO
Recording Engineer

Testi

Awa ti juba ka to wole
Ati juba kawa to wole
Ajuba Olorun Baba, Ajuba Olorun Omo
Emi mimo Adaba Orun wa se ba re
Ayiyintan Eledumare
Ayiyintan ni Jesu to wa saye
Omu Igba nla wa funmi eda eniyan
Kabiyesi re Olodumare
Emi Mimo ese o, Emi awon woli
Iwo kuku lagbara wa
Emi Mimo ese
Bi a ba n gbo mimo mimo
Bi a ba n gbo ogo ogo
Emaya si otun, ema ya sosi
Ile Oluwa lemi n gba lo
A fe ri o o, Aladewura
Orun esi ooo
Orun kini, Orun Keji
Orun Keta, Orun Kerin
Orun Karun, Orun Kefa
Orun Keje, Esi sile
Orun esi ooo
Sebi O tin se Olorun Ayeraye
Okiki re ni mo gbo, ni mo se wa o
Maje ki ota yo mi o
Je n fayo lo
Oti wa miri
Oti pemi waye
Oso mi dalayo o
Jesu ti Nazareti ooo
Olorun Ayeraye
Ire aye mi gba funmi
Olorun Ayeraye
Odi gbere o di gbo
Odi gbere o di gba
Ibanuje aye mi
Odi gbere o di gbo
Fowo ase nla
Gbadura mi goke lo
Ki lo n ro, owo lo n ro
Ki lo kun, Igbala kun bi ojo
Ki lo sele lode orun o
Ara n san Oluwa mi de
Ti Oluwa ni ile
Aye ateku re
Ki ile oni to su wa se temi
Temi ni okan se, Oba Ogo
Written by: Adebayo Oladipupo Temitope
instagramSharePathic_arrow_out

Loading...