Crediti
PERFORMING ARTISTS
Niniola
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Niniola Apata
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Johnny Drille
Producer
Testi
[Verse 1]
I was forsaken
A fallen believer
Don’t forsake me
I know I'm a sinner
[Verse 2]
Lord, please wash all my sins away
Make me whiter than snow
You brought me out of poverty
I say
[Chorus]
Mo yọ, mo yọ
Mo yọ, mo yọ
Give me a hand
Mo yọ, mo yọ
This is my song
Give me a heart
Ti ba ri owo re laiye mi
Mo yọ, mo yọ
Mo yọ, mo yọ
[Verse 3]
Eleti igbaroye
My one and only
The God that always listen to me
Close my eyes and talk to You
You're always there to order my steps
[Verse 4]
In the time of trouble
You're there to deliver me
In the time of pain
You soothe it away
In the time of joy
[Verse 5]
Ọrọ buruku mo kọ
Ọrọ iya mo kọ ọ
Ire ni temi
Ọrọ buruku mo kọ
Ọrọ iya mo kọ ọ
[Chorus]
Mo yọ, mo yọ
Mo yọ, mo yọ
Give me a hand
Mo yọ, mo yọ
This is my song
Give me a hand
Ti ba ri, ti ba ri ọwọ rẹ laye mi
Mo yọ mo yọ (Give me a hand)
Mo yọ mo yọ (Give me a hand)
[Verse 6]
Oju mi ti ri eti mi ti la
Oju mi ti ri eti mi ti la
Oju mi ti ri eti mi ti la
Mo ti ri Ọlọrun mi
Ọwọ Rẹ to bale mi
Oju mi ti ri eti mi ti la
Mo rire gba oh mo rire gba
Mo rire ra mo rire gba ye
[Chorus]
Mo yọ mo yọ
Mo yọ mo yọ
Give me a hand
Mo yọ mo yọ
This is my song
Give me a hand
Ti ba rire
Ti ba ri ọwọ Rẹ laye mi
Mo yọ, mo yọ
Mo yọ, mo yọ
[Refrain]
Ti ba rire
Ti ba ri ọwọ rẹ laye mi
Ti ba rire
Ti ba ri ọwọ Rẹ laye mi
Written by: Niniola Apata