Video musicale
Video musicale
Crediti
PERFORMING ARTISTS
Adeyinka Alaseyori
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Adeyinka Alaseyori
Songwriter
Testi
[Verse 1]
Bo ṣe ma n ṣe niyẹn, bo ṣe ma n ṣe niyẹn
O maa n sẹru dọba, o maa n sẹru dọba
B'Adaniwaye ṣe ma n ṣe leyii o
Bo ṣe ma n ṣe niyẹn
O maa n sẹru dọba, o maa n sẹru dọba
[Chorus]
Tori, wọn ni ko saye loke
O waaye fun mi loke
O gbogo fọlẹ mi
Iyanu lorukọ rẹ
Aye ni ko saye loke mọ
O waaye fun mi loke
O gbogo fọlẹ mi
Iyanu lorukọ rẹ
[Verse 2]
Awọn kan lowo titi
Wọn ni afawọn afawọn
Awọn kan lọla titi wọn lafawọn at'Ọlọhun
Igbati Adaniwaye de o mu talaka joko saarin wọn
Wọn n sọrọ bi ọba, wọn wa n sọrọ bi ọba
[Chorus]
Wọn ni ko saye loke
O waaye fun mi loke
O gbogo fọlẹ mi
Iyanu lorukọ rẹ
Aye ni ko saye nibẹ mọ
O waaye fun mi nibẹ o
O gbogo fọlẹ mi
Iyanu lorukọ rẹ o
[Bridge]
Is that your testimony? Wherever you are common everybody lift your voice, sing along
[Verse 3]
Alaragbayida de saye mi ara ire lowa fimi da
O faye mi dabira agba iyanu loju araye
Alaragbayidade saye mi o faye mi dabira
Ara ire lowa fimi da, agba iyanu loju araye
[Chorus]
Aye ni ko saye nibẹ mọ
O create space fun mi loke
O gbogo fọlẹ mi
Iyanu lorukọ rẹ
Gbogbo eniyan ni ko saye nibẹ
O waaye fun mi nibẹ o
O gbogo fọlẹ temi
Iyanu lorukọ rẹ
[Verse 4]
Nibi iṣẹ rẹ wọn ni kosi promotion
O fun ẹ ni promotion
Sebi ogbogo fọlẹ rẹ ni
Iyanu lorukọ rẹ
Awọn to n bọṣọ si ọ lọrun tẹlẹ telẹ, o wa dọga lori wọn
O gbogo fọlẹ rẹ ni
Iyanu lorukọ rẹ
Awa ta ti fori ogo kiri
Awa dẹni to n jọba lori ero
O gbogo fọlẹ wa ni
Iyanu lorukọ rẹ
Ko sowo ko sowo la n sọ tẹlẹ
Ọpọlọpọ owo lo ko de sapo wa
O gbogo fọlẹ awa ni
Iyanu lorukọ rẹ
Awa to n le lori aga fun ọlọla
Awan joko pẹlu awọn ọlọla
O gbogo fọlẹ mi ni
Iyanu lorukọ rẹ
[Chorus]
Wọn ni ko saye nibẹ
O waaye fun mi nibẹ
O gbogo fọlẹ mi
Iyanu lorukọ rẹ
Aye ni ko saye nibẹ mọ
O waaye fun mi nibẹ
O gbogo fọlẹ mi
Iyanu lorukọ rẹ
[Verse 5]
Sọ asọtẹlẹ ohun rere saye rẹ eeeh
Ẹnu ẹni la fi n kọ me jẹ
Iyẹn ni Yoruba wi
Bibeli lo wa kede rẹ
Ọmọ kiniun a ma ṣalaini
Ebi a si maa pa wọn
Awa ta a gbẹkẹle Oluwa
A ki i yoo ṣalaini ohun to dara
Eyi ni ileri rẹ o
O gbogo fọlẹ mi
Iyanu lorukọ rẹ
[Verse 6]
There are levels to testimonies
There are levels to breakthrough
Ipele to wa ko jẹ dupẹ
O gbogo fọlẹ rẹ
[Chorus]
Wọn ni ko saye nibẹ mọ
O waaye fun mi nibẹ
O gbogo fọlẹ mi
Iyanu lorukọ rẹ
Aye ni ko saye loke
O waaye fun mi loke
O sọ mi dogo agbaye loju aye
Iyanu lorukọ rẹ
[Chorus]
Wọn ni ko saye loke
O waaye fun mi loke
O gbogo fọlẹ mi
Iyanu lorukọ rẹ
Wọn ni ko saye loke
O waaye fun mi loke
O gbogo fọlẹ mi
Iyanu lorukọ rẹ
Written by: Adeyinka Alaseyori