album cover
Kalaa
album cover
Kalaa è stato pubblicato il 8 dicembre 2023 da Azuri come parte dell'album Kalaa - Single
8 dicembre 2023
EtichettaAzuri
LinguaEnglish
BPM151
Melodicità
Acousticità
Valence
Ballabilità
Energia

Testi

[Chorus]
Kala kan lọ ọ jẹ, kala kan lọ ọ jẹ, kala kan lọ ọ jẹ, kala kan lọ ọ jẹ
Kala kan, kala kan, kala kan lọ ọ jẹ, kala kan lọ ọ jẹ, kala kan lọ ọ jẹ
-1, -2, ẹ ni duro wo part 2
1-2 eniduro wo part 2
1-2 eniduro wo part 2
1-2 eniduro wo part 2
[Refrain]
Alujannu lo n gbe wa
Beyani atita
Alujannu lo n gbe wa
Beyani atita
[Bridge]
Ẹ wọnnu wọn, wọnnu wọn, wọnnu wọn, wọnnu wọn, wọnnu wọn, wọnnu wọn
A a mọnu wọn, mọnu wọn, mọnu wọn, mọnu wọn, mọnu wọn, mọnu wọn
[Verse 1]
Ọpapa parada dagger mi da?
Wọn fẹ fun mi Coke ni jọ Fanta mi da?
Tẹwo si mi aza mi da?
No info no payment wire mi da?
Ijauta agba ni now, wọn fẹ mumi'lẹ ni paki hacker mi da?
Ọmọ Ibadan mi o dẹ mind Bodija, kala woju mi bi ọmọ Bodija
Aljazera, sabatical, apa mo lọ'nu store Zara mi da?
Awọn Peter Rufai ẹ lọ wa'bi gba ki Cardi B to lọ di Kadija
Za
[Bridge]
Ẹ wọnnu wọn, wọnnu wọn, wọnnu wọn, wọnnu wọn, wọnnu wọn, wọnnu wọn
A a mọnu wọn, mọnu wọn, mọnu wọn, mọnu wọn, mọnu wọn, mọnu wọn
Ẹ wọnnu wọn, wọnnu wọn, wọnnu wọn, wọnnu wọn, wọnnu wọn, wọnnu wọn
A a mọnu wọn, mọnu wọn, mọnu wọn, mọnu wọn, mọnu wọn, mọnu wọn
[Chorus]
Kala kan lọ ọ jẹ, kala kan lọ ọ jẹ, kala kan lọ ọ jẹ, kala kan lọ ọ jẹ
Kala kan, kala kan, kala kan lọ ọ jẹ, kala kan lọ ọ jẹ, kala kan lọ ọ jẹ
-1, -2, ẹ ni duro wo part 2
1-2 eniduro wo part 2
1-2 eniduro wo part 2
1-2 eniduro wo part 2
[Refrain]
Alujannu lo n gbe wa
Beyani atita
Alujannu lo n gbe wa
Beyani atita
[Verse 2]
Wọn ni ẹ ni pe ko sowo
Ṣebi inu igbẹ lowo wa
Igboro dẹ lọga wa
A wa nibi towo wa
Money money money money
When I pull up is foreign
Brother abeg get that money
To ba lọ broke ko ni funny
Eruku ganja le wọn sita
Surulere jo wọ Shitta
Jaye foreign gbọmọ mẹta
Awa nita
Written by: Jimoh idowu wasiu
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...