album cover
32
album cover
00:05
02:00
00:00
02:22
Ultimi 7 giorni
32 è stata scoperta più frequentemente a circa 40 secondi dall'inizio la canzone durante la settimana passata

Testi

[Verse 1]
Ẹ jẹ́ ká catch cruise
Ẹ wa fẹ thirty two
Iṣẹ́ Ọlọ́run adìtú
Àwọn kan carry do
[Verse 2]
Life na roller coaster
Mo ṣe n rọra jó Makosa
Pari òwe yìí
Àyé o le, fún ẹni tó mọ way
[Chorus]
Jẹleosinmi kidergattern
Ki irẹsi tó jinmi, pe Hilda Baci
I'm dulling never (Ayayayaya)
Àbí ọ̀nà Ìsẹ́yìn lẹ gba? (You are on your own)
Ọ̀yọ́ ma lẹ wà (Abi Bauchi)
Tafa Balewa
[Verse 3]
Ko pọ, kó dùn, ko pẹ
Ìyá, ìyá takùn walẹ
Ka rowo ṣe fuja ko plenty
Owó ni o wá, fi ija lẹ
Aroye ò gbowó ní bank
Kò saye fún n'gbàtí n'gbàtí
[Verse 4]
Kére o
Atara àtẹbí
Ẹ pin ko kárí Parle G
Is causing pandemic
Kọkọrọ alátẹ toun tàtẹ ni
[Verse 5]
Now I put everyone for the mood
Wọ́n n jẹ́ d'Agarawu
O ṣènìyàn, Alamu
Ọrẹ wá Aina Òrosùn
Ṣo mọ pe pay day kò mọjọ́, kò mọṣù
Wọn a jó dẹndẹ
Agba wòlíì ṣí pẹpẹ
[Verse 6]
Ẹ jẹ́ ká catch cruise
Ẹ wa fẹ thirty two
Iṣẹ́ Ọlọ́run adìtú
Àwọn kan carry do
[Verse 7]
Life na roller coaster (Roller coaster)
Mo ṣe n rọra jó Makosa
Pari òwe yìí (Pari òwe yìí)
Àyé o le (Àyé o le), fún ẹni tó mọ way
[Chorus]
Jẹleosinmi kidergattern
Ki irẹsi tó jinmi, pe Hilda Baci
I'm dulling never
Àbí ọ̀nà Ìsẹ́yìn lẹ gba?
Ọ̀yọ́ ma lẹ wà (Abi Bauchi)
Tafa Balewa
[Verse 8]
Bọbọ Aláṣàkaṣà
Now I put everyone for the mood
Wọ́n n jẹ́ d'Agarawu
O ṣènìyàn, Alamu
Written by: Olajuwon Oluwaseun Opeyemi
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...