album cover
Kaa
album cover
Kaa è stato pubblicato il 1 dicembre 2023 da davisKING come parte dell'album Kaa - Single
1 dicembre 2023
EtichettadavisKING
BPM130
Melodicità
Acousticità
Valence
Ballabilità
Energia

Testi

Aaaah! Aaaah!
Aaaah! Aaaah!
Aaaah! Aaaah!
Aaaah! Aaaah!
Eni ba m'ore Oluwa, kaa
Eni ba m'ore Jesu, kaa
Eni ba m'ore Oluwa, kaa
Eni ba m'ore Jesu, kaa
Kpirikiti, kpirikiti, kpirikiti, kpirikiti, kpirikiti!
Semkpobrie!
Aaaah! Aaaah!
Aaaah! Aaaah!
Eyin le fun mi l'ayo o
Oba to segun funmi
Tin ba l'egberun ahon
Ko to yin Baba o
Sebi eyin le gbogo f'ole
T'etun dami lare
N'itori e l'emi n s'ope
Eleduwa sa ni Baba o
Ko ma si Oba to da b'Ire
Ninu gbogbo agbaye
Ko ma si Oba to da b'Ire
Ninu gbogbo agbaye
Eni ba m'ore Oluwa, kaa
Eni ba m'ore Jesu, kaa
Eni ba m'ore Oluwa, kaa
Eni ba m'ore Jesu, kaa
Kpirikiti, kpirikiti, kpirikiti, kpirikiti, kpirikiti!
Semkpobrie!
Aaaah! Aaaah!
Aaaah! Aaaah!
S'emi no re Oluwa
Ikoko ijosi ma ni
Aje ile o l'owun o pani
Oso ile o l'owun o seni
Sugbon mo wa ni Oluwa
Soun l'on gbemi leke
N'itori e l'emin sope
Eleduwa sa ni Baba o
Ko ma si Oba to da b'Ire
Ninu gbogbo agbaye
Ko ma si Oba to da b'Ire
Ninu gbogbo agbaye
Eni ba m'ore Oluwa, kaa
Eni ba m'ore Jesu, kaa
Eni ba m'ore Oluwa, kaa
Eni ba m'ore Jesu, kaa
Kpirikiti, kpirikiti, kpirikiti, kpirikiti, kpirikiti!
Semkpobrie!
Aaaah! Aaaah!
Aaaah! Aaaah!
Ko ma si Oba to da b'Ire
Ninu gbogbo agbaye
Ko ma si Oba to da b'Ire
Ninu gbogbo agbaye
Eni ba m'ore Oluwa, kaa
Eni ba m'ore Jesu, kaa
Eni ba m'ore Oluwa, kaa
Eni ba m'ore Jesu, kaa
Kpirikiti, kpirikiti, kpirikiti, kpirikiti, kpirikiti!
Semkpobrie!
Aaaah! Aaaah!
Aaaah! Aaaah!
Eni ba m'ore Oluwa, kaa
Eni ba m'ore Jesu, kaa
Eni ba m'ore Oluwa, kaa
Eni ba m'ore Jesu, kaa
Kpirikiti, kpirikiti, kpirikiti, kpirikiti, kpirikiti!
Semkpobrie!
Written by: Olumide Oyinloye
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...