クレジット

PERFORMING ARTISTS
Masterkraft
Masterkraft
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Bella Shmurda
Bella Shmurda
Songwriter
Zlatan
Zlatan
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Masterkraft
Masterkraft
Producer

歌詞

[Intro]
Wọn ṣepe ko le mu mi yeah
Wọn ṣepe
Wọn duro de (Ayii)
Ki lo de to n ṣepe? (Master, master, master)
Ayaya (Ibilẹ)
Shmurda ya Zlatan
Ayii kapaichumarichumaripaco
Ah ah
[Verse 1]
Ṣe tori mo ṣana ṣana wọn binu lọwọ
Wọn pe panapana ko wa pana
Wọn pana mi ti wọn buga mi ti
O n binu ọmọ ologo na your calamity
Is it my fault? that everyday na Christmas for our side?
A dẹ ma n gazo
Emi ni father wọn ahh
O ṣa mọ? 100 police sẹ ko to soldier kan (Ah ah)
[Verse 2]
Ijaya si wọn ah
Ta lo figbaju gba gari wọn?
Wọn fẹ figa gbaga Igbobi l'ọn pada lọ
Wọn tapa wọn, wọn tẹsẹ wọn (Ahh kuro nbẹ)
Ijaya si wọn
Ta lo figbaju gba gari wọn?
Wọn figa gbaga Igbobi l'ọn lọ
Wọn tapa wọn, wọn tẹsẹ wọn (Bandage da?)
[Verse 3]
Brother don't bother me
Oluwa cover me
Whatever you wish me, good or bad?
Back to sender ni ah ya
Ori elepe lepe n lọ
Ẹni egbere, mo jẹlọ
Ọlọkọ ṣa ma wa mi lọ
Blessing from junction to junction
[Chorus]
Ha hallelu
Hallelujah Oluwagbemileke ma gawu
Lẹyin adura oh atawẹ fọjọ meje
My darling every little thing you want
I'm ready to do it more
Nnkan ti mo ṣe lawọn gan-an fẹ ṣe (Master, master)
To ba ṣe wọn ma jiya gan-an
Turn it up
Master
Wọn nnkan ti mo ṣe lawọn gan-an fẹ ṣe (Master, master)
T'ọn ba ṣe wọn ma jiya gan-an
[Verse 4]
Ọga yin ni ẹ gba fun
Tẹ ba ri ẹ yago fun
Ọga ni kẹ ye fariga
Seven star general
Military movement leleyi
Awa leeyan Babangida (Ahh wo)
[Verse 5]
Ẹni ba bẹ ma ku ah
To ba ti ja ẹ tete sọ fun
OG a ma wọn yin nlẹ tẹ ba lọ yaju ahh
Ba ṣe nice naa la ṣe daju (Ahh wo)
[Verse 6]
Ẹni ba be ma ku
Nigba ti ko si rizla a n fa kanaku
K'ọn ran wa lọwọ wọn kana ku
Wọn ṣakọ ku
Mo ti jẹlọ k'ọn to laju
[Verse 7]
Brother don't bother me (Astala astala)
Oluwa cover me (Bella j'ẹ ọ mọ)
Whatever you wish me, good or bad?
Back to sender ni ah ya (Ayii)
Ori elepe lepe n lọ
Ẹni egbere mo jẹlọ
Ọlọkọ ṣa ma wa mi lọ
Blessing from junction to junction
[Chorus]
Ha hallelu
Hallelujah Oluwagbemileke ma gawu
Lẹyin adura oh atawẹ fọjọ meje
My darling every little thing you want
I'm ready to do it more
Nnkan ti mo ṣe lawọn gan-an fẹ ṣe
T'ọn ba ṣe wọn ma jiya gan-an
Turn it up
Master
Wọn nnkan ti mo ṣe lawọn gan-an fẹ ṣe (Master, master)
T'ọn ba ṣe wọn ma jiya gan-an
[Outro]
Hallelu
Hallelujah Oluwagbemileke
Ma gawu
Lẹyin adura ohh atawẹ fọjọ meje
It's Stormatique mix
Written by: Bella Shmurda, Zlatan
instagramSharePathic_arrow_out

Loading...