歌詞
Mà kán'jú o
Mà sáré o
Tó ba fẹ d'ọ̀lọ̀rọ̀ layé
Mà dúró o
Mà kán'jú o
Mà sáré o
Tó ba fẹ d'ọ̀lọ̀rọ̀ layé
Mà dúró o
Iṣẹ́ tó ba n ṣe
Tẹrámọ̀, tẹrámọ̀, tẹrámọ̀
Bó j'orin lo ba nkọ
Tẹrámọ̀, tẹrámọ̀, tẹrámọ̀
Ike lo ma n te
Tẹrámọ̀, tẹrámọ̀, tẹrámọ̀
Ijó lo mò jó o
Tẹrámọ̀, tẹrámọ̀, tẹrámọ̀
Iṣẹ́ tó ba n ṣe
Tẹrámọ̀, tẹrámọ̀, tẹrámọ̀
Bó j'orin lo ba nkọ
Tẹrámọ̀, tẹrámọ̀, tẹrámọ̀
Ìke lo má n tè
Tẹrámọ̀, tẹrámọ̀, tẹrámọ̀
Ijó lo mò jó o
Tẹrámọ̀, tẹrámọ̀, tẹrámọ̀
Wọn ni isẹ́ yá
Ká lọ sisẹ́
Ìwọ l'eré yá
Ká má l'odè aríyà
Keep on hustle
Mà ṣe bàyẹn
Dàkún, ye má ṣe mèlẹ
Work o, work o
Make you no push truck o
Ọmọ ìyámi, mà lọ ṣuègbẹ
No pain, no gain o
I say no play no game o
Ẹnu o ṣe o, ẹnu o rà bra box
No life, no flame o
Iṣẹ́ tó ba n ṣe
Tẹrámọ̀, tẹrámọ̀, tẹrámọ̀
Bó j'orin lo ba nkọ
Tẹrámọ̀, tẹrámọ̀, tẹrámọ̀
Ìke lo má n tè
Tẹrámọ̀, tẹrámọ̀, tẹrámọ̀
Ijó lo mò jó o
Tẹrámọ̀, tẹrámọ̀, tẹrámọ̀
Try to help your brothers
Oluwa go help you too
We rise by lifting others
Na somebody help you too
Torí ko s'álàbaru
Ọmọ ìyá mi, keep on hustle
Tó ba tẹrámọ̀, àje, you gonna bubble
Put more effort, tẹrámọ̀
Yè f'òwúrọ̀ mà lo mọ
Tó ba n gbérá, gbé súnmò
Tó ba n fèwọ́, yèrá fún
Mà kán'jú o
Mà sáré o
Tó ba fẹ d'ọ̀lọ̀rọ̀ layé
Mà dúró o
Mà kán'jú o
Mà sáré o
Tó ba fẹ d'ọ̀lọ̀rọ̀ layé
Mà dúró o
Iṣẹ́ tó ba n ṣe
Tẹrámọ̀, tẹrámọ̀, tẹrámọ̀
Bó j'orin lo ba nkọ
Tẹrámọ̀, tẹrámọ̀, tẹrámọ̀
Ìke lo má n tè
Tẹrámọ̀, tẹrámọ̀, tẹrámọ̀
Ijó lo mò jó o
Tẹrámọ̀, tẹrámọ̀, tẹrámọ̀
Put more effort, tẹrámọ̀
Tẹrámọ̀ o, tẹrámọ̀
Yè f'òwúrọ̀ mà lo mọ
Destiny tó n kọ Fuji, tò n ko jẹ
Tó ba n gbérá, gbé súnmò
Tó ba n fèwọ́, yèrá fún