歌詞

Èmi ni, èmi lẹni náà Ọkùnrin mẹ'ta àtààbọ' tán forin kọ Èmi ni, èmi l'ọmọ náà Ọkùnrin mẹ'rin àtààbọ', wọn ń tẹnu mọ Mo lanu, mo sọ'rọ' Mo yọ àáké, mo fọ' ọ'rọ' Ọmọ ọlọọfọọrọ Mo j'àkàrà ọfọọrọ Èmi ni áà, emi ni óò Èmi mà l'ẹni tán sọ nígboro Èmi ni yáà, èmi ni yóò Àwọn màmá gan ń sòró ní pópó Wọn lémi l'àkọkọ Wọn lémi l'àkọkọ oh-oh Wọn lémi l'àkọkọ oh-oh Wọn lémi l'àkọkọ oh-oh Èmi ni ọkùnrin náà Táwọn màjèsín ń sọ pé m'orin gan Èmi ni, èmi l'ọmọ náà Gbogbo ará àdúgbò ló ń tẹnu mọ Èmi bàbá olówó Mo ṣòwò, mo jèrè Ìwà àti ọpọlọ ló ń lò Àwọn ọ'tá ti ru póò Èmi ni áà, emi ni óò Èmi mà l'ẹni tán sọ nígboro Èmi ni yáà, èmi ni yóò Àwọn ọmọge ń rèdí ní pópó Wọ'n lémi l'àkọ'kọ' (Ìwọ l'àkọ'kọ') Wọ'n lémi l'àkọ'kọ' oh-oh (Ìwọ l'àkọ'kọ' oh-oh) Wọ'n lémi l'àkọ'kọ' oh-oh (Ìwọ l'àkọ'kọ' oh-oh) Wọ'n lémi l'àkọ'kọ' oh-oh (Iwo l'àkókó oh-oh) Wọ'n lémi l'àkọ'kọ' (Ìwọ l'àkọ'kọ') Wọ'n lémi l'àkọ'kọ' oh-oh (Ìwọ l'àkọ'kọ' oh-oh) Wọ'n lémi l'àkọ'kọ' oh-oh (Ìwọ l'àkọ'kọ' oh-oh) Wọ'n lémi l'àkọ'kọ' oh-oh (Ìwọ l'àkọ'kọ' oh-oh)
Writer(s): Amarachukwu Kebonku, Ashimi Ibrahim Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out