クレジット
PERFORMING ARTISTS
Jhybo
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Jibola Toriola
Songwriter
歌詞
[Intro]
Yee Oluwa ah ah ah
Awa ọmọ rẹ ti de o
[Chorus]
Baba God awa ọmọ rẹ de
Lati gbohun ẹbẹ wa soke si ọ
Gẹgẹ bi o ti gbọ adura Elijah
Baba gbọ adura mi
Gẹgẹ bi o ti gbọ adura Elijah
Baba gbọ adura mi
Baba God awa ọmọ rẹ de
Lati gbohun ẹbẹ wa soke si ọ
Gẹgẹ bi o ti gbọ adura Elijah
Baba gbọ adura mi
Gẹgẹ bi o ti gbọ adura Elijah
Baba dakun gbọ adura mi o
[Verse 1]
Okay Baba wọn n pariwo pawọn loogun
Adura nikan ni mo mọ ni mo fi n kankun
Mo mọ palawo wa pẹlu adahunṣe
Ẹru mi n bẹ lọwọ ẹ Baba ba mi gbe
Cos I believe in You only
I'm a sinner I no dey form say I too holy
All my enemies You dribble with no mercy
I no dey brag ọmọ na to learn lesson
Adabi ti n ba ro ti wọn laida
Wọn fowo ṣogun but oogun yẹn o favour wọn
Adabi ti mummy mi ba keṣe wọn
Wọn pọfọ ṣugbọn Oluwa o ma gbede wọn
Well I'm just alone with my God
I tire for this world so I pray make I port
I believe in my Lima Jehovah nay sword
Yes Jehovah na my boss
[Chorus]
Baba God awa ọmọ rẹ de
Lati gbohun ẹbẹ wa soke si ọ
Gẹgẹ bi o ti gbọ adura Elijah
Baba gbọ adura mi
Gẹgẹ bi o ti gbọ adura Elijah
Baba gbọ adura mi
[Verse 2]
Ọba mimọ wa gbe wa ga o, uh yeh
Ma ṣe jẹ ki iji aye yii ko wa lọ o
Tete wa sinu aye wa
Tori iwọ ni amọna
Ẹmi ọrun sọkale oo
Tete wa sinu aye wa
Tori iwọ ni amọna
Ẹmi ọrun sọkale oo
[Verse 3]
Baba yee ṣaanu mi
Bi mo ṣe n rinrinajo maa tẹle mi
Nitori ile-aye gbọgbọn
Ile-aye su mi
Ẹmi ọrun sọkalẹ, yee oh
[Chorus]
Baba God awa ọmọ rẹ de
Lati gbohun ẹbẹ wa soke si ọ
Gẹgẹ bi o ti gbọ adura Elijah
Baba gbọ adura mi
Gẹgẹ bi o ti gbọ adura Elijah
Baba gbọ adura mi
[Outro]
Baba yee ṣaanu mi
Bi mo ṣe n rinrinajo maa tẹle mi
Nitori ile-aye gbọgbọn
Ile-aye su mi
Ẹmi ọrun sọkalẹ, yee oh
Written by: Jibola Toriola