クレジット

COMPOSITION & LYRICS
Abiola Onipede Choicest
Abiola Onipede Choicest
Songwriter

歌詞

Jiji ti moju l'owuro
Mo dide,mo gb'ori mi mu
Mo b'elada mi soro,ko gbomi
Ijade mi l'owuro yi o,ko murewa o
Ki nkore oja wale o,ki nma k'elesu lona bi mo ti njade lo o
Orimi segbe leyin mi o,ki nkore wa sile
Bi mo se njade lo
Je nmure pada wale
Edumare gbo o f'ohun mi s'ase
K'aje kowa miri
Ki nkore ayo lopolopo wale
Ipadabowale mi Olorun je o yori si rere
Owuro mo wayi o oo
Osan atale mi dowo e
Ko san mi o titi dale ki nle yin o o
Bami se temi Edumare
Kori olola ma pemi ran nise
Tori igba ni gbogbo nkan nile aye
Aye mi dowo re o bami se temi ko yanju
Segan midogo,kemi le ma yin o o
Bi mo se njade lo
Je nmure pada wale
Edumare gbo o f'ohun mi s'ase
Jesu l'olusoaguntan mi
Ore eni yi kiiye
Ko sewu bi mo je tire
Tohun si je temi titi
Jo fona mi han mi
Kemi ma s'ori olori ku
Kemi ma sakobata fegbe mi
Bamise,koju ma timi
Kaiye ma bere polorun mi da
Bami gberu mi o
Edumarw ko yori
Bi mo se njade lo
Je nmure pada wale
Edumare gbo o f'ohun mi s'ase
Written by: ABIOLA CHOICEST
instagramSharePathic_arrow_out

Loading...