歌詞

Lawh mahfuz lodo olohun, ire ni moyan, ireee Lawh mahfuz lodo olohun, ire ni moyan, ire Kinto sadua emi nkirun Ire ni moyan, ire Mo nyan nafila mose ibaadah, ire ni moyan, ire Wakati marun f'oba olohun, ire ni moyan, ire Robbana Atina Fi duniya Hassanatan Wafil akhirati, hassanatan Waqina adzaba naar Interlude Yah allah eru re ni, to tinpe e fungba tope, mowa gbesi ayo mi ni Oore ni mofe allahu soore, f'eru re o Yah allah eru re ni, to tinpe e fungba tope, mowa gbesi ayo mi ni Oore ni mofe allahu soore, f'eru re o Allaaah! Yah allah eru re ni, to tinpe e fungba tope, mowa gbesi ayo mi ni Oore ni mofe allahu soore, f'eru re o Yah allah eru re ni, to tinpe e fungba tope, mowa gbesi ayo mi ni Oore ni mofe allahu soore, f'eru re o Allahumma iftahliy Abwabal khayr Wa abwaba ssalamati Abwaba s-sihati Wa abwaba ni-imati Wa abwabal barakati Wa abwabal qu-wwati Abwabal mawadati Abwaba r-rahmati Abwaba rizqi (Allah) Abwabal ilimi (Allah) Abwabal magfirati Abwabal Jan-nnati Yah arhama rohimeena Yah allah eru re ni, to tinpe e fungba tope, mowa gbesi ayo mi ni Oore ni mofe allahu soore, f'eru re o Emi kii s'eru alaimore, oun timofe bamise, maso p'óòsé ilahi K'oju mati oruko re ni, iwo lo fun igbin ni ìkáráhún, kito male da lenu re Won so p'ógà burewa MashaaAllah! Wallahi ogun aso, koto ògà lo lojumo Iwo lo da l'aso aponle, s'ore funmi lona iyanu K'enemy ma mo b'ose se, kon rimi konwa tûba Awon iya toti njewon Ki won bimi f'ona abayo Kinle so funwon pe iwo lose Yah allah eru re ni, to tinpe e fungba tope, mowa gbesi ayo mi ni Oore ni mofe allahu soore, f'eru re o Tebi tara nkigbe iwo ni, niwon nreti pe toba de Gbogbo ase toba pa, gbogbo e niwon ma tele Ati awon tiwon ju e lo, bonse rie nonti dide Lori chair pe ko joko, àjànàkú o mo niwon B'asemo pe erin tobi Olohun o wo sisanra, kinihun tiò to won L'allahu se loba, mashaallah Oore olohun ona iyanu Allahu sefunmi, kinle so funwon p'ewo lose (Allah) Yah allah eru re ni, to tinpe e fungba tope, mowa gbesi ayo mi ni Oore ni mofe allahu soore, f'eru re o Òshì tin tani debi arinfin, ìshé tinseni debi abuku, ebi tinpani dele ota naa Allaaah! Iya tinjeni dele ana, dakun mafi sadanwo Owo topo tio letan Ola tin weni láwèda Ibukun tonle oshi lo Muheeba ton mu okiki wa Sefunmi o yah robbi Aranse toju àwúré lo Ewe lamo ton sunko Ola olohun làjénjétán Yah allah eru re ni, to tinpe e fungba tope, mowa gbesi ayo mi ni Oore ni mofe allahu soore, f'eru re o Ha, kilonfe gan ti ola olese, ore to tin lebo tipe Kadua e o legba, ishoro lonba e finra Qurani ti juwe ashiri, l'anabi ba juwe abayo Ji loru ko joko adura o, toba d'igba tile ba mo Mu sàrãa ni sise, nigbagbo pelu suuru o Toba dabipe o ma fe pe, kofe fun e nigbayen ni Tori asiko tiwo fe yen, boya (Allah) o ripe ole fa akoba Konipe koni jina, yio dae loun pelu oore Yah allah eru re ni, to tinpe e fungba tope, mowa gbesi ayo mi ni Oore ni mofe allahu soore, f'eru re o Abdul lateef oriyomi Akanni won npe oruko mi Si t'owo si ipe ola Mo wan niyi l'oko ati ile Ni gursu pelu ìwò óòrùn Ìlà óòrùn won momi naa Moni fans ni gbogbo agbaye Tiwon nfemi dokan dokan o K'olohun kemi ke awon eyan mi Mafi aisan da wa ni ágó árá Kale gbadun arawa pe Okiki to bunmi allah Ko bamise l'alodale (Amin) Yah allah eru re ni, to tinpe e fungba tope, mowa gbesi ayo mi ni Oore ni mofe allahu soore, f'eru re o Allaaah la ilaha illa allahu Lailaha illa allah Allaaah la ilaha illa allaaah Lailaha illa allah Allaaaaaaa ah, allaaaah Allah la ilaha illa allahu Lailaha illa allah Bi haqqi illa allah, lailaha illa allah Wa bihaqqi arshihi, lailaha illa allah Bihaqqi adzomatihi, lailaha illa allah Wa bihaqqi seyyidina, lailaha illa allah Rosuli llah, lailaha illa allah Istejibu dua-anaa, lailaha illa allah La tansa murodanaa, lailaha illa allah Bihaqqi ila allah, lailaha illa allah Bihaqqi ila allah, lailaha illa allah
Writer(s): Oriyomi Sanni Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out