クレジット

PERFORMING ARTISTS
Yusuf Abubakar Sodiq t/as CDQ
Yusuf Abubakar Sodiq t/as CDQ
Performer
Wasiu Alabi Odetola t/as Pasuma
Wasiu Alabi Odetola t/as Pasuma
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Yusuf Abubakar Sodiq t/as CDQ
Yusuf Abubakar Sodiq t/as CDQ
Composer
Wasiu Alabi Odetola t/as Pasuma
Wasiu Alabi Odetola t/as Pasuma
Composer
PRODUCTION & ENGINEERING
Sunday Ginikachukwu Nweke t/as Masterkraft
Sunday Ginikachukwu Nweke t/as Masterkraft
Producer

歌詞

[Chorus]
Ọga nla ni mo jẹ
Beere mi ninu abẹtẹ, ọga nla ni mo jẹ
Lekki de Mushin Olosha, ọga nla ni mo jẹ
Sego ki lo kan boss, ọga nla ni mo jẹ
Actor lo n ṣe wahala, ọga nla ni mo jẹ
Beere mi ninu abẹtẹ, ọga nla ni mo jẹ
Lekki de Mushin Olosha, ọga nla ni mo jẹ
MC ki lo kan boss, ọga nla ni mo jẹ
Actor lo n ṣe wahala, ọga nla ni mo jẹ
[Verse 1]
To ba bẹ o ma tẹ (Ọlọhun)
Swag bi ẹni tẹgbẹ n dun buh ara ni mo fi gbẹ
I'll rather be a king in the jungle than to be a dog in the city
These **** wanna pull me back but o shock that I did it
Packaging l'ọn fi n disguise
All these rappers are fish pie
No Godfather ṣugbọn Ọlọhun wa lori hustle yii, e sure me die
Mo Kunle Poly wọn piu piu
Fọwọ kọ mi lọrun kẹ chill chill
Gbe kẹkẹ lọ bi COVID-19 mi o tanna wẹbi, keep distance
[Chorus]
Ọga nla ni mo jẹ
Beere mi ninu abẹtẹ, ọga nla ni mo jẹ
Lekki de Mushin Olosha, ọga nla ni mo jẹ
Sego ki lo kan boss, ọga nla ni mo jẹ
Actor lo n ṣe wahala, ọga nla ni mo jẹ
Beere mi ninu abẹtẹ, ọga nla ni mo jẹ
Lekki de Mushin Olosha, ọga nla ni mo jẹ
MC ki lo kan boss, ọga nla ni mo jẹ
Actor lo n ṣe wahala
[Verse 2]
Ọga nla ni mo jẹ, mo jẹ
Ọmọ igboro gan-an n jẹ
Wọn ti n gbọ lati 80's, 90's, okay awọn genZ gan-an jẹ
Awa k'ọn fine ni stainless
T'ọn ba gbemu ẹ le wọn pẹlu stainless
Ọmọ eeyan kan ni watch ni o
Ẹjẹ, ṣebi Oluwa lo ni timing
Certified bars lawa n bi sori mic anytime, ah
Oluwa lo ni banging (Banging)
Ma sọ po gbọ, ma sọ po gba o
Eeyan mi, ma sọ po gbọ, ma sọ po gba o
Ọga nla ni wa ni everywhere Jibola
[Chorus]
Ọga nla ni mo jẹ
Beere mi ninu abẹtẹ, ọga nla ni mo jẹ
Lekki de Mushin Olosha, ọga nla ni mo jẹ
Sego ki lo kan boss, ọga nla ni mo jẹ
Actor lo n ṣe wahala, ọga nla ni mo jẹ
Beere mi ninu abẹtẹ, ọga nla ni mo jẹ
Lekki de Mushin Olosha, ọga nla ni mo jẹ
MC ki lo kan boss, ọga nla ni mo jẹ
Actor lo n ṣe wahala, ọga nla ni mo jẹ
[Outro]
Kinibolo, kejibolo, panbolo kunbokun
Ma bo naa ni jẹ a bo lẹẹkan
A n bo naa ni Paso o
CDQ j'ọn mo
Written by: Wasiu Alabi Odetola t/as Pasuma, Yusuf Abubakar Sodiq t/as CDQ
instagramSharePathic_arrow_out

Loading...