album cover

Fefenefe

88Afro-Beat2026
album cover
Fefenefeは、アルバム『{albumName}』の一部として2026年5月17日にVibe cityによりリリースされましたFefenefe - Single
アルバムFefenefe - Single
リリース日2026年5月17日
レーベルVibe city
言語English
BPM115
メロディック度
アコースティック度
ヴァランス
ダンサビリティ
エネルギー

ミュージックビデオ

ミュージックビデオ

歌詞

[Verse 1]
My baby fẹfẹnẹfẹ
Awọn kan l'ọn gbowo, baby awọn kan lo n ṣẹ
No weapon shall prosper baby t'ọba laṣẹ
My baby slow whine fun mi sẹsẹlẹnsẹ
[PreChorus]
Awọn ọmọ ọba ma lo n nawo yii o ṣa mọ ọmọ ọba lo n paṣẹ
Awọn kan l'ọn gbowo, baby awọn kan lo n ṣẹ
Before you start to dey kolo mi mo ya gbe body mi fẹsẹfẹ
My baby slow whine fun mi sẹsẹlẹnsẹ
[Chorus]
Uh uh uh
Baby mi why o
Ọmọ to ṣan yii o
Baby ma pa mi o
My baby o ṣa ti ri bi mo ṣe wa yii o
Ọmọ mi to dun bi palmi o
Baby ma pa mi o
[Verse 2]
Ọmọ olo mi o kere she dey chop my libido
O loun o lọle mọ, o fẹ tẹpa sibi o
In her short knicker pempe she dey touch her pretty toes
My baby nibi o
O tun ma n jẹṣẹ DPO
[Verse 3]
Bazooka baki yii tap (Yeba)
Ọmọ Ijebu le si e wa
O ni koun da k'emi da
O ni ka jọ ṣe wọle wọde ginika
Ti ba ni ko jo baby dance
Girl have been reading your mind
And I no go like make I take you be mine
[PreChorus]
Awọn ọmọ ọba ma lo n nawo yii o ṣa mọ ọmọ ọba lo n paṣẹ
Awọn kan l'ọn gbowo, baby awọn kan lo n ṣẹ
Before you start to dey kolo mi mo ya gbe body mi fẹsẹfẹ
My baby slow whine fun mi sẹsẹlẹnsẹ
[Chorus]
Uh uh uh
Baby mi why o
Ọmọ to ṣan yii o
Baby ma pa mi o
My baby o ṣa ti ri bi mo ṣe wa yii o
Ọmọ mi to dun bi palmi o
Baby ma pa mi o
[Outro]
She dey chop my libido
O loun o lọle mọ, o fẹ tẹpa
Written by: Balogun Faruq Tobiloba

Shazam フッター

言語を選択:
Google Play Store
Apple App Store
Chrome Web Store
Galaxy Store

フォローしてください

Loading...