가사

Ojo agbara na ti osan d'oru Ta so ijo mimo kale.ye Irawo meje loyo ni oke orun Awon eiye won ke luli Ojo agbara na ti osan d'oru Moni Taso ijo mimo kale Irawo meje loyo ni oke orun Awon eiye won ke luli Moni Awon eiye won ke luli Luli ore ofee Irawo meje loyo ni oke orun Awon eiye won ke luli Awon eiye won ke luli ooo ye eh yee Luli ore ofee Moni irawo meje loyo ni oke orun Awon eiye won ke luli Awon eiye won ke luli
Writer(s): Emmanuel Adetayo Adebisi Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out