Ope은(는) {albumName} 앨범에 수록된 곡으로 2015년 12월 11일일에 Afreal Unique Concepts에서 발매되었습니다.Ope
BPM
멜로디에 강한 음악
잘 정의된 음악 패턴에 따른 명확하고 기억에 남는 멜로디를 갖춘 곡입니다. 이 척도가 높은 곡은 일반적으로 연주나 보컬 라인이 명확하고 기억에 남는 것이 특징입니다.
어쿠스틱 악기 중심
곡이 전자 음악이나 디지털 합성 음악이 아닌 어쿠스틱 악기(예: 피아노, 기타, 바이올린, 드럼, 색소폰)를 얼마나 많이 사용하는지를 나타내는 척도입니다.
발랑스
곡의 화성과 리듬 요소를 통해 전달되는 음악적 긍정성 또는 감정적 톤입니다. 높은 쾌감은 행복, 흥분, 희열의 감정에 해당하며, 낮은 쾌감은 슬픔, 분노, 우울과 연관됩니다.
춤추기 좋은 음악
템포의 안정성, 리듬 패턴, 비트 강조 등 여러 요인의 조합을 통해 곡이 춤추기에 얼마나 적합한지 정하는 척도입니다. '춤추기 좋은' 곡의 특징은 일정한 템포, 반복적인 음악 구조, 강한 다운비트입니다.
에너지
트랙의 강렬함은 템포, 역동성, 음악적 밀도에 영향을 받을 수 있습니다. 에너지가 높은 곡은 강렬한 리듬과 풍부한 악기 편곡으로 구성되는 반면, 에너지가 낮은 곡은 음악적으로 간결하고 느린 템포가 특징일 수 있습니다.
가사
Nipa ipa ko, kii s'agbara l'oro se ri b'o se ri
B'o ti wu ko ri Oluwa s'olododo f'awon to gba A gbo
Oye aye o ye ni to sugbon o da wa loju Alaanu l'Olorun wa
A gbe ni leke, Oluke ni, Oluyan ni sola
Aseyiowu O se o Baba t'o fi wa dara iyanu (Iba Iba Iba)
Iba o
Iba f'Olorun Eledumare to l'ogo oooo (iba)
Iba Iba Iba naa ni o (Iba o)
Iba Iba Iba o
A juba, a juba, f'Olorun to ni gbogbo ogo, Oun ni (Iba o)
Iba l'awa f'aye wa ju oo (Iba o)
Iba, a juba Re, Iwo nikan lo ni gbogbo ijuba a wa (Iba o)
Iba Iba Iba
Ope ni fun o Edumare, Oba to laye
Adani magbagbe Oba Oke to segun fun wa
Bi ko ba se 'Wo too seyi fun wa ki la a ba wi o
Ope wa ree o, Oba to to gb'oju le
A mo riri oore t'Oo se fun wa o, Oba to to gb'oju le
Okeere ni mo gbe wa o, mo gburo ise Oluwa
Ta lo dabi Re ninu aanu, adani ma gbagbe eni
Bi'da keji ba sele, Oo sa ma j'Olohun lo ni
O ka wa m'awon t'Oo pe, t'Oo yan
Oba to to gb'oju le
O ka wa m'awon t'Oo s'aanu fun
A o le dupe tan lai lai lai lai
You are the Lord above all the earth
Kabi o o si o
You are the Lord above all the earth
Kabi o o si o
Oju mi ti ri, eti mi ti gbo
Iyanu Re yi aye ka
Mo gbo ninu eri awon eniyan mimo
Mo ri ninu itan, emi gangan ni itan
Gbogbo ise Re daa da'a da'a da'a ni
Aburu kankan o t'odo Re wa
Ohun gbogbo lo le yi pada
Sugbon rara t'ododo Re ko
Kabiyesi oooo, mo se ba Re
Oba to ju gbogbo oba lo
Kabiyesi ooo
Kabiyesi o mo se 'ba Re
Oba to ju gbogbo oba lo
Afuye gege ti o see gbe
Jigbinni jigbinni bi ate ileke
Kabiyesi o mo se 'ba Re
Oba to ju gbogbo oba lo
Afuye gege ma ma see gbe
Jigbinni jigbinni bi ate ileke
Kabiyesi o mo se 'ba Re
Oba to ju gbogbo oba lo
Mo se 'ba Re o, mo se 'ba Re
Mo f'ori bale mo gb'owo soke
Mo se'ba Re o, mo se 'ba Re
Ni 'rele okan mi ni mo wari
Kabiyesi o mo se 'ba Re
Oba to ju gbogbo oba lo
Kabiyesi o
Kabiyesi o mo se 'ba Re
Oba to ju gbogbo oba lo
Aigbagbo bila temi l'Oluwa
Oun yoo si dide fun igbala mi
Ki n sa ma gb'adura
Oun o se 'ranwo
'Gba Krist' wa l'odo mi ifoya ko si
B'ona mi ba su, Oun lo sa n to mi
Ki n sa gboran sa Oun o si pese
B'ona mi ba su o, Oun lo sa n to mi
Ki n sa gboran sa Oun o si pese
Bi 'ranlowo eda
Bi 'ranlowo eda gbogbo saki
Oro t'enu Re n so yoo bori dandan
Hallelujah
Hosanna
Hallelujah
Hossanah
Hallelujah l'awon orun nke
Hossanah
Awa aye naa nke tiwa, hallelujah
Hossanah
Hallelujah
Hossanah (hossanah hossanah l'awa nko)
Hallelujah (Hossanah)
Gbogbo iseda n f'ori bale f'ooko Re, Hallelujah
Hossanah
Hallelujah
Hossanah
Our Father
We bless You
Olutoju wa, we bless You
We bless You
Eni to l'emi to fun wa mi, we bless You
We bless You
Eni t'O fi 'ranwo fun wa, we bless You
We bless You
Eeeh Oluwa, Eeeeh ehhh Oluwa
Eeeeh Oluwa o b'ona ba su
Oluwa f'ona han wa, Oluwa o
Eeeh Oluwa, Eeeeh ehhh Oluwa o
Eeeeh Oluwa o b'ona ba su
Oluwa f'ona han wa, Oluwa o
Ife t'O fi han ko je ki n ro pe
Yio fi mi sile ninu wahala
Oun to mu mi de bi s'olododo lati sun mi siwaju
Ko ni fi mi sile bo ti le wu ko ri o
Iranwo ti mo si
Iranwo ti mo si n ri lojojumo
O ki mi l'aya pe emi yoo laaja
Olorun agbaye
You are mighty
Olorun to wa ninu awon orun to ju awon orun lo (You are mighty)
Ori obiri aye lo n gbe imole lo fi saso bora o (You are mighty)
O f'orun se 'le,
O f'aye s'apoti itise maa s'ola Re lo (You are mighty)
You are mighty, You are wonderful,
You are awesome, oruko Re niyen (You are mighty)
Olorun agbaye (You are mighty)
Sebi 'Wo lo f'oju orun saso bora
Olorun agbaye o, You are mighty o
Olorun agbaye o You are mighty
Sebi 'Wo lo f'oju orun saso bora
Olorun agbaye o, You are mighty o
Oruko Oluwa ile iso agbara ni
Olododo sa wo'nu re, o ri iye
Emi naa, mo sa wo'nu re, mo ri iye
Oruko Re ti niyin to (Oluwa Oluwa)
Oluwa, Oluwa wa, oruko Re ti niyin to
Oluwa Oluwa Oluwa
Oluwa, Oluwa wa, oruko Re ti niyin to
Alagbara l'Olorun wa
Agbara agbara agbara yi po o, agbara
Oba to ba riru omi okun wi, agbara Re po
Agbara agbara agbara yi po o, agbara
A wo 'gba aarun, ma gb'eje l'ooko Re
Agbara agbara agbara yi po o, agbara
Oba to f'aanu tan 'mole s'ona awon to gb'oju s'oke si
Agbara agbara agbara yi po o, agbara
O f'agbara gba ni lowo alagbara gbangba ti n f'owo agbara je ni niya
Agbara agbara agbara yi po o, agbara
Gbogbo iseda n wariri ni'waju agbara Re
Agbara agbara agbara yi po o, agbara
Iba o
Iba f'Olorun Eledumare to ni gbogbo ogo (Iba)
Iba Iba a (Iba)
A juba, a juba, gbogbo ijuba wa tire ni (Iba)
Olorun to ni gbogbo ogo, iba f'ooko Re (Iba)
Gbogbo iseda n f'ori bale ni'waju Re (Iba)
Iba Iba Iba a
Ise Re po, o po, o po, o po gaan ni (Iba)
Awon ise iyanu t'Oo ti se, ta lo le ka won tan? (Iba)
Ta lo le so ewa Re to po, to po gaan ni? (Iba)
Iba Iba Iba Iba (Iba)
Gbogbo eemi mi, gbogbo wiwa mi, tire lo je, mo juba (Iba)
Titi aye ni ma ma se'ba Re lojojumo (Iba)
Maa sin O d'opin igba mi, Iba Iba (Iba)
Iba aaa
Written by: RR, Sola Allyson

