album cover
Otilo
26,215
African
Otilo은(는) 앨범에 수록된 곡으로 2022년 10월 24일일에 YBBM에서 발매되었습니다.Otilo - Single
album cover
발매일2022년 10월 24일
라벨YBBM
멜로디에 강한 음악
어쿠스틱 악기 중심
발랑스
춤추기 좋은 음악
에너지
BPM125

뮤직 비디오

뮤직 비디오

크레딧

실연 아티스트
Qdot
Qdot
실연자
프로덕션 및 엔지니어링
2Ty
2Ty
프로듀서

가사

(2T Uponthebeat)
Qdot l'oruko mi
Omo'mo Moriamo
Omo o le buru titi, k'afi f'ekun pa je
E bami gbe Oluwa tobi, Lekan ti yi pada
Ko mu'gbo mo (Loud lon fa)
Ko fa cigar (Shisha lon fa)
Ko gba Jedi (Molly lon gba)
T'oba ti gb'oja, ma na soldier
Ko mu'gbo mo oh (Loud lon fa)
Ko fa cigar (Shisha lon fa)
Ko gba Jedi (Molly lon gba)
T'oba ti gb'oja, ma na soldier
(Otilo)
Owo t'oba wo "wan-wan" (otilo)
Oole t'oba wo'nu Eko (otilo)
Ajawo yin (otilo)
Iyawo yin (otilo)
L'ati Mainland (otilo)
Ma bo ni Lekki (otilo)
Lekki ninu loh loh (otilo)
A ma shey Uber fun (otilo)
A ma shey Utuba fun (otilo)
Tal'efin ta'yin? (otilo)
Ab'ori nta yin? (otilo)
Iyawo oga yin (otilo)
Iyawo egbon yin (otilo)
T'oba ti fi si (otilo)
Won ba pada yo-o (otilo)
Omo t'en gbe wa (otilo)
Awa l'agbe lo oh (otilo)
Okada l'efi gbe wa (otilo)
Benz l'afi gbe lo oh (otilo)
A ma ra Fendi fun (otilo)
A ma ra Gucci fun (otilo)
T'oba ti g'eshin kutakuta (otilo)
Kole mo'na ile mo (otilo)
Ma bo l'odo Gattuso (otilo)
Elegushi wo'nu Oniru (otilo)
T'omo ti mu Azul (otilo)
E wa ni "k'oma ba sun" (otilo)
Fa-la-ti-do (otilo)
Re-mi-re-do (otilo)
So-so-mi-re-do-do (otilo)
Fa-so-mi-la-ti-do (otilo)
Omo o le buru titi, k'afi f'ekun pa je
E bami gbe Oluwa tobi, Lekan ti yi pada
Ko mu'gbo mo (Loud lon fa)
Ko fa cigar (Shisha lon fa)
Ko gba Jedi (Molly lon gba)
T'oba ti gb'oja, ma na soldier
Ko mu'gbo mo oh (Loud lon fa)
Ko fa cigar (Shisha lon fa)
Ko gba Jedi (Molly lon gba)
T'oba ti gb'oja, ma na soldier
(Otilo)
Oya, soh pe "otilo" (otilo)
Izz gone-gone (otilo)
T'apo e bati fuye (otilo)
L'arin awon omo oro (otilo)
Awon omo "b'ani, a toro" (otilo)
Awon omo "b'ani, a jagba" (otilo)
Bawo l'era shey gbe sugar? (otilo)
Talo y'owo l'apo picker? (otilo)
Oko t'oba pa'na (otilo)
A sanwo "omo taku" (otilo)
T'eba pe ija agbagba (otilo)
Ma pe ija omode (otilo)
Alagbara lon gb'owo ita (otilo)
Oun wa charger (otilo)
Ko mo pe won ti yo 'je (otilo)
T'oba ni "o d'apo e mu" (otilo)
Ihahin na Lagos (otilo)
T'oba ka e mo woro (otilo)
Woro si woro (otilo)
O ma d'eshu (otilo)
T'oba lo 'je 'mu Jesu (otilo)
Oba wa ni Sheffield (otilo)
Mo mo Arowolo (otilo)
Mo mo Alhaja Bolashere (otilo)
L'America (otilo)
Lanre Typical (otilo)
Riliwan Kula (otilo)
Ato Mukaila (otilo)
Mo mo Bunmi Obakoya (otilo)
Alagbe mo Obelu (otilo)
Mo mo Dende (otilo)
Omo o le buru titi, k'afi f'ekun pa je
E bami gbe Oluwa tobi, Lekan ti yi pada
Ko mu'gbo mo (Loud lon fa)
Ko fa cigar (Shisha lon fa)
Ko gba Jedi (Molly lon gba)
T'oba ti gb'oja, ma na soldier
Ko mu'gbo mo oh (Loud lon fa)
Ko fa cigar (Shisha lon fa)
Ko gba Jedi (Molly lon gba)
T'oba ti gb'oja, ma na soldier
(2T on the Mix)
Written by: Qdot
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...