가장 인기 있는지난 7일
00:25 - 00:30
Soapy은(는) 지난 주에 약 25 초 시점에에 가장 많이 검색된 곡입니다.
00:00
00:05
00:25
00:45
00:50
01:05
01:30
01:45
01:55
02:10
02:15
02:20
02:45
00:00
02:54
뮤직 비디오
뮤직 비디오
크레딧
실연 아티스트
Rexxie
프로그래밍
Naira Marley
보컬
작곡 및 작사
Chisom Ezeh
작곡가
Azeez Fashola
가사
프로덕션 및 엔지니어링
Rexxie
프로듀서
가사
[Intro]
O t'ẹsẹ'le bọ
Yahoo ni babalawo
Ole l'everybody
Ẹni ilẹ mọ ba ṣa ni barawo
(Barawo, barawo, barawo) Mọ ba ṣa ni barawo
[Verse 1]
O tẹsẹ'le bọ
Yahoo ni babalawo
Ole l'everybody
Ẹni ilẹ mọ ba ṣa ni barawo
O fẹ ṣe'ka fun mi
Mi o l'ogun mo ni Kurani
Mo dẹ n ṣ'adura mi
Bi m ṣe n ṣ'adura mi
Allah n gba'dura mi
A ti lọ a ti de
Ẹni ori yọ o di'le
Ẹni ba lọ l'o ba de
Igba ti m pada de
N'ṣe l'ọn de mi l'ade
K'ade ko pẹ l'ori
Ki bata k'o pe l'ẹsẹ
K'awọn ọta mi kan l'ẹsẹ
[Bridge]
Inside life
O ti ri 5 Alive
Inside life
O ti ri Deeper Life
Inside life
Awọn kan n jẹ'ya
Awọn kan n chop life
Inside life
Awọn kan n ṣ'epe
Awọn kan n jẹ'wa
[Chorus]
Jo soapy, soapy
Kirikiri n jo soapy
Jo soapy, jo soapy, soapy
Ikoyi prison n jo soapy
Jo soapy
Ninu cell EFCC wọn n jo soapy
Jo soapy
T'o o ba ni'yawo n'le k'o jo soapy
Soapy, soapy, soapy
Bọda yi n jo soapy
Soapy, soapy
Ab'ẹyin naa soapy?
Soapy, soapy
Single father n jo soapy
Soapy, ma lọ lo OMO t'o ba lọ n soapy, soapy
[Verse 2]
Ṣ'o d'owo mọ?
O wa sọ p'o o mọ Naira
O wuwo l'ọwọ
Iwọ ṣaa ṣẹ si Naira
Aja fẹ de'na d'ẹkun
Kekere ẹkun o ma n s'ẹgbẹ aja
Wọn n bẹ ni, Ma fọ
Awọn naa o fẹ wahala
I just wanna make Mama proud
They want to make Mama cry
Mama, you gonna cry no more
T'ẹ ba sun'kun gan ẹ o sọ'kun ayọ
Ti m ba n jo k'ẹ ba m yọ
K'ọrọ mi ja s'ayọ
Inside life, Inside life
Do what I want 'cause it's my life
[Bridge]
Inside life
O ti ri 5 Alive
Inside life
O ti ri Deeper Life
Inside life
Awọn kan n jẹ'ya
Awọn kan n chop life
Inside life
Inside life, awọn kan n ṣ'epe
Awọn kan n jẹ'wa
[Chorus]
Jo soapy, soapy
Kirikiri n jo soapy
Jo soapy, soapy
Ikoyi prison n jo soapy
Jo soapy
Ninu cell EFCC wọn n jo soapy
Jo soapy
T'o o ba ni'yawo n'le k'o jo soapy
Soapy, soapy, soapy
Bọda yi n jo soapy
Soapy, soapy
Ab'ẹyin naa soapy?
Soapy, soapy
Single father n jo soapy
Soapy, ma lọ lo OMO t'o ba lọ n soapy
Soapy
Written by: Azeez Fashola, Chisom Ezeh

