크레딧

실연 아티스트
Moporsh
Moporsh
실연자
Shittu Tosin
Shittu Tosin
백그라운드 보컬
작곡 및 작사
Olumide Moradeyo
Olumide Moradeyo
가사

가사

[Verse 1]
Animal le wear agbada
Ọmọ owo lo n wọ Bottega
Animal le say nada
Mo ṣeba Alpha and Omega
I-iyawo mi ma jẹ a ja
Ita la wa, ita la wa sẹ
She say I be talaka, mo ra palasa, mo fi palasa ṣiṣẹ
Kolo, kolo, to ba ri mi mo ti kolo, kolo oh
Ojo, Ojo, o wa mu mi ranti Ojo, Ojo oh
Polo, Polo, high fashion mo wọ Polo, Polo
Mi o soro, soro, Ayo Maff mi o soro, soro oh
[Chorus]
Ifẹ lo sọ mi di mugu
Igbalode baby no voodoo
O woju, o woju mi
Ẹyinju o woju mi
Ifẹ lo sọ mi d'ọmọ oro
Igbalode baby o da mi loro
O woju, o woju mi
Ẹyinju o woju mi
[Verse 2]
O ni talika o raye wa
Ni mo ṣe kanra mọ hustle mi
Ẹ gba mi lọwọ Shukusheka
Oju ri kọmọpẹ to lo Face ID
O ni pe mi o pawo, mi o dawo
Mo kanra mọṣẹ, mi o gba loan
Saro ma lọ soro mi
Ọmọ Igbalode no dey pressure mi
And if I cast ṣebi na to change my IP
Ogun owo no fit buy you Bentley
Na lazy man no fit cure poverty
Ko sẹni ta bi mọ pẹlu oṣi
Rọra sare motor ko ma kọlu kẹkẹ
Rọra ṣe ko ma lọ tẹ
Ibi ti ma de, ma debẹ ẹ
So I no go fit to rest
[Chorus]
Ifẹ lo sọ mi di mugu
Igbalode baby no voodoo
O woju, o woju mi
Ẹyinju o woju mi
Ifẹ lo sọ mi d'ọmọ oro
Igbalode baby o da mi loro
O woju, o woju mi
Ẹyinju o woju mi
Written by: Olumide Moradeyo
instagramSharePathic_arrow_out

Loading...