크레딧
실연 아티스트
EmmaOMG
오케스트라
Goodness Patrick Adeosun
백그라운드 보컬
Olakunle Awopeju
오케스트라
Tobi Emmanuel Osinaya
백그라운드 보컬
Bajulaye Victor Oluwaseun
백그라운드 보컬
Ayomiotitan Olateju
베이스 기타
Love Abolade
백그라운드 보컬
Cynthia Princewill Alfred
백그라운드 보컬
Dan Edmund
리드 기타
Ojo Gloria
백그라운드 보컬
Ajayi Joseph Oluwaseun
피아노
Esther Cecilia James
백그라운드 보컬
Olamide Adeleye
건반
Yimika Akinola
오르간
Daniel Alan
합창단
Olakanye Iyanuoluwa Omobolanle
합창단
Eyinolu Opeyemi Ayomide
합창단
Michelle Obilor
합창단
Racheal Igbarie
합창단
Sarah Alasan
합창단
Ossai Chioma
백그라운드 보컬
Kegbeyale Olubukola
합창단
Iyanuoluwa Christiana Oke
합창단
Oluwasholafunmi Favour Rapheal
합창단
Omolara Oladimeji
합창단
Georgina Inemesit Eka
합창단
Dolapo Oladele Awodele
합창단
Esther Olorunfemi
합창단
Olaniyi Temitope Mary
합창단
Rhema Joseph Ahons
백그라운드 보컬
Adeosun Oluwatoyin Esther
합창단
Olami Deborah Olusola
합창단
Hassan bukola
합창단
Woye Itimi Enifome Jennifer
합창단
Chioma Odimegwu
합창단
Daibiloloari Young
합창단
Oladokun Abosede Deborah
합창단
Oreoluwa Oyesagba
합창단
Loveth Oghenekevwe
합창단
Damilola Esther Dada
합창단
Deborah Nofiu
합창단
TeminiJesu Rebecca Obe
합창단
Akinwasola Anuoluwapo
합창단
Blessing Ituen
합창단
Tèmilolúwa Akínwándé
합창단
Idowu Daniel
합창단
Olamide Oyasagba
합창단
Anuoluwapo Maxwell Amusu
합창단
Omenogor Daniel
합창단
Timileyin Akoore
합창단
Adeeyo Timilehin
합창단
Oluwafemi Gold Olayode
합창단
Samuel Dare Ojuotimi
합창단
Aiyepada Gabriel
합창단
Dada Joshua
합창단
Toby Davyd
합창단
Omotoye Ayooluwa
합창단
John Sounds
합창단
John Osemudiamen
합창단
Tomiwa Adeshina Taiwo
합창단
AYOMIDE DAVID KEHINDE
합창단
Moses ID Olukayode
타악기
작곡 및 작사
Emmanuel Edunjobi
작사가 겸 작곡가
EmmaOMG
편곡자
프로덕션 및 엔지니어링
EmmaOMG
프로듀서
Soundmindpro
마스터링 엔지니어
가사
Nitori iwo ni o da inu mi
Iwo ni o so mi di odidi ninu iya mi
Ki a to da mi tan ni oti ri mi
O ti ko iye ojo ti a pin fun mi sinu iwe re
Ki ojo aye mi tile to bere rara
N o ko orin iyin si oluwa, ni iwon igba ti mo ba wa laaye
N o ma ko orin iyin si olorun, ni iwon igba ti emi mi ba’n be
Oooh oooh oooh ooooh
Oooh oooh oooh ooooh
Can somebody sing oooh
Oooh oooh oooh ooooh
Oooh oooh oooh ooooh
Iwo lo ni eje mi
Iwo lo ni egun mi
Iwo lo ni ara mi
Iwo lo ni emi mi
Iwo lo ni eemi mi
Iwo lo ni iwalaye mi
Iwo lo ni aye mi, Jesu
Iwo lo ni eje mi
Iwo lo ni egun mi
Iwo lo ni ara mi
Iwo lo ni emi mi
Iwo lo ni eemi mi
Iwo lo ni iwalaye mi
Iwo lo ni aye mi, Jesu
Aye mi n f’ogo fun o
Aye mi n f’ogo fun o o
Aye mi n f’ogo fun o
Aye mi n f’ogo fun o o
Oooh oooh oooh ooooh
Oooh oooh oooh ooooh
Iwo lo ni eje mi
Iwo lo ni egun mi
Iwo lo ni ara mi
Iwo lo ni emi mi
Iwo lo ni eemi mi
Iwo lo ni iwalaye mi
Iwo lo ni aye mi, Jesu
Iwo lo ni eje mi
Iwo lo ni egun mi
Iwo lo ni ara mi
Iwo lo ni emi mi
Iwo lo ni eemi mi
Iwo lo ni iwalaye mi
Iwo lo ni aye mi, Jesu
Aye mi n f’ogo fun o
Aye mi n f’ogo fun o o
Omi ara mi ati eje ara mi won korin aleluya si baba, won n f’ogo fun o
Aye mi n f’ogo fun o o
Iwo lo ni owuro mi
Iwo lo ni osan mi
Iwo lo ni ale mi
Iwo lo ni gbogbo ojo aye mi
Iwo lo ni ibere mi
Iwo lo ni opin mi
Iwo lo ni aye mi, Jesu
Iwo lo l’owuro mi o
Iwo lo ni owuro mi
Iwo lo ni osan mi
Iwo lo ni ale mi
Iwo lo ni gbogbo ojo aye mi
Iwo lo ni ibere mi
Iwo lo ni opin mi
Iwo lo ni aye mi, Jesu
Aye mi n f’ogo fun o
Aye mi n f’ogo fun o o
Omi ara mi ati eje ara mi wo’n k’orin aleluya s’oba mimo won n f’ogo fun o
Aye mi n f’ogo fun o
Won ni iyin ola ni fun o Olorun metalokan to joko lori ite ogo won n f’ogo fun o
Aye mi n f’ogo fun o o
Ori mi, ejika mi, orukun mi ati ese mi won ko’rin aleluya s’oba mimo won n f’ogo fun o
Aye mi n f’ogo fun o o
Mo f’aye ati’fe mi fun
Odo aguntan, t’oku fun mi
Je kin le je olotito, Jesu olorun mi
Mo wa f’eni t’oku fun mi
Aye mi yio si dun pupo;
Mo wa f’eni t’oku fun mi, Jesu olorun mi;
Mo gbagbo pe iwo n gbani;
‘Tori iwo ku k’emi le la;
Emi yio si gbekele o, Jesu olorun mi;
Mo wa f’eni t’oku fun mi
Aye mi yio si dun pupo;
Mo wa f’eni t’oku fun mi, Jesu olorun mi;
Iwo t’oku ni Kalfari ;
Lati so mi d’ominira;
Mo y’ara mi s’oto fun o, Jesu olorun mi;
Mo wa f’eni t’oku fun mi
Aye mi yio si dun pupo;
Mo wa f’eni t’oku fun mi, Jesu olorun mi;
Tor’aye mi n f’ogo fun o
Aye mi n f’ogo fun o o
Iwo lo ni mi, Iwo lo ni gbogbo oun ti mo ni, ati oun to mo je
Aye mi n f’ogo fun o o
Won ni kini mo ja mo, mo ni eje Jesu ni mo ja mo
Oun lo fun mi ni iye ayeraye
Aye mi n f’ogo fun o o
Omi ara mi ati eje ara mi wo’n k’orin aleluya s’oba mimo l’ori ite ogo
Aye mi n f’ogo fun o o
Won wa so wipe won ni
Ogo, Ola, Iyin, ni fun o Jehovah
Mo wa n ke Aleluya, Aleluya
Ogo, Ola, Iyin, ni fun o Jehovah
Mo wa n ke Aleluya, Aleluya
Ogo, Ola, Iyin, ni fun o Jehovah
Mo wa n ke Aleluya, Aleluya
Ogo, Ola, Iyin, ni fun o Jehovah
Mo wa n ke Aleluya, Aleluya
Emi f’oribale fun o oo, mo jo ijo ayo si o oo
Mo wa n ke Aleluya, Aleluya
Gbogbo ohun to wa ni inu mi wo’n f’ohun si baba mi l’orun o
Mo wa n ke Aleluya, Aleluya
Emi f’oribale fun o oo, mo jo ijo ayo si o oo
Mo wa n ke Aleluya, Aleluya
Gbogbo ohun to wa ninu mi wo’n f’ohun si baba mi l’orun o
Mo wa n ke Aleluya, Aleluya
Mo wole f’oba ologo julo, mo k’orin ipa ati ife re o
Mo wa n ke Aleluya, Aleluya
Nitori ti o seun, anu re duro titi lailai
Mo wa n ke Aleluya, Aleluya
Èmi yóò gbé ọ ga, Ọlọ́run mi, obami
Èmi yóò yin orúkọ rẹ̀ láé àti láéláé
Ni ojojumo ni emi yio ma yin o.
Ti n o mayin oruko re lai ati lailai
Oluwa tobi iyin si ye lopo lopo
Awamaridi si ni titobi re
Lati iran de iran ni a o ma yin ise re
Ti a o si ma soro ise agbara re
Emi yio ma se asaro lori ewa ogo olonla re
Ati ise iyanu re
Eniyan yio ma kede ise agbara re ti o yani lenu
Emi yio si ma polongo ti tobi re
Won yio ma p’okiki bi ore re ti po to
Won yio si ma k’orin soke nipa ododo re
Alanu ni oluwa, olore si ni
Ki yara binu, ife re ti ki’ye si po
Oluwaseun fun gbogbo eniyan,
Anure si’n be lori gbogbo oun ti o da
Oluwa gbogbo oun ti oda ni yio ma dupe lowo re
Awon eniyan mimo re yio si ma yin o
Won o ma royin ogo ijoba re
Won o si ma so nipa agbara re
Lati mu awon eniyan mo agbara re
Ati ewa ogo ijoba re
Ijoba ayeraye ni ijoba re
Yi o si ma wa lati iran de iran
Olooto ni oluwa ninu gbogbo oro re
Oloore ofe si ni ninu gbogbo ise re
Oluwa gbe awon tin subu lo dide
Osi gbe gbogbo awon ti a teri won ba naro
Oju gbogbo eniyan n wo oo
Osi fun won ni ounje won ni asiko
Iwo la owo re
Osi te gbogbo eda alaye lorun
Ah, Oluwa ooo
Olododo ni oluwa ninu gbo gbo ona re
Alanu sini ninu gbogbo ise re
Oluwa sunmo gbogbo awon tin pe
Ani awon tin pe tokan tokan
Oun te ife awon ti o beru re lorun
Osi n gbo igbe won, osi ngba won
Oluwa da gbogbo awon ti o fe si
Sugbon yio pa gbogbo awon eniyan buburu run
Enu mi yio ma soro iyin Oluwa
Ki gbogbo eda ma yin oruko re lai ati lailai
(Tongues)
Mo wa nke halleluyah, halleluyah
Gbogbo oun to wa ninu mi wo’n f’ohun si baba mi lorun
Mo wa n ke Aleluya, Aleluya
Ogo, Ola, Iyin, ni fun o Jehovah
Mo wa n ke Aleluya, Aleluya
Ogo, Ola, Iyin, ni fun o Jehovah
Mo wa n ke Aleluya, Aleluya
Ogo, Ola, Iyin, ni fun o Jehovah
Mo wa n ke Aleluya, Aleluya
Ogo, Ola, Iyin, ni fun o Jehovah
Mo wa n ke Aleluya, Aleluya
Aye mi n f’ogo fun o
Aye mi n f’ogo fun o o
Omi ara mi ati eje ara mi won korin halleluyah si baba, won n f’ogo fun o
Aye mi n f’ogo fun o
Hallelujah!!!
Written by: Emmanuel Edunjobi

