Oversability
28,598
Music
Oversability은(는) 앨범에 수록된 곡으로 2025년 11월 7일일에 Dvpper Digital에서 발매되었습니다.Kaizen - EP
가장 인기 있는지난 7일
00:00 - 00:05
Oversability은(는) 지난 주에 처음 몇 초 동안에 가장 많이 검색된 곡입니다.
00:00
00:10
00:40
00:55
01:00
01:05
01:10
01:15
01:25
01:30
01:50
02:00
02:25
02:40
03:00
00:00
03:12
뮤직 비디오
뮤직 비디오
크레딧
실연 아티스트
BhadBoi OML
보컬
작곡 및 작사
BhadBoi OML
작곡가
프로덕션 및 엔지니어링
Damilola "Dapper" Akinwunmi
책임 프로듀서
Jayfred
프로듀서
가사
[Verse 1]
As at now mo n temperamental
Kọ apala pẹlu vocabulary (Baami)
Haruna Ishola no do reach this one (Baami)
Musiliyu Ishola no do pass this one
Onilu mi ba mi kogi lelu
Iya iyawo rẹ o ku ni ṣẹyun
Rosco grandma rẹ o ku ni salọ
Na producer you be you no be God o
[PreChorus]
Na we dey sing ọmọ na we dey fo
Awa la l'Eko ọmọ iwin lo ni igbo
Ọba Dubai ti sọ pe ka ma mugbo
Ko ku sọmọ naa ti o jọṣẹ
Ye, na we dey sing ọmọ na we dey fo
Awa la l'Eko ọmọ iwin lo ni igbo
Ọba Dubai ti sọ pe ka ma mugbo
Ko ku sọmọ naa ti o jọṣẹ
[Chorus]
Oversability wan kill me
Versatility wan wound me
Balienciaga lẹsẹ mi
Richard Mille lọwọ mi
Mo ti mọ pe Naija ṣi ma dun
K'Ọlọhun ma jẹ a mọya
K'Ọlọhun ma jẹ a jẹba lọ school
Ọmọ better Naija ṣi ma dun
[Chorus]
Oversability wan kill me
Versatility wan wound me
Balienciaga lẹsẹ mi
Richard Mille lọwọ mi
Mo ti mọ pe Naija ṣi ma dun
K'Ọlọhun ma jẹ a mọya
K'Ọlọhun ma jẹ a jẹba lọ school
Ọmọ better Naija ṣi ma dun
[Verse 2]
If life no fair lo calamine lotion
Heart of man is deeper than ocean
Emeka ẹ ma ma ja mọ o
Odumodu pink, Odumodu black
O ṣe ọkọ Halimotu, ọkọ Shadia
O o lowo, o n fun wa l'idea
E don tey, e don tey, man I've heard enough
Ki iku pa ẹ iwọ pẹlu idea ẹ
[PreChorus]
Na we dey sing ọmọ na we dey fo
Awa la l'Eko ọmọ iwin lo ni igbo
Ọba Dubai ti sọ pe ka ma mugbo
Ko ku sọmọ naa ti o jọṣẹ
Ye, na we dey sing ọmọ na we dey fo
Awa la l'Eko ọmọ iwin lo ni igbo
Ọba Dubai ti sọ pe ka ma mugbo
Ko ku sọmọ naa ti o jọṣẹ
[Chorus]
Oversability wan kill me
Versatility wan wound me
Balienciaga lẹsẹ mi
Richard Mille lọwọ mi
Mo ti mọ pe Naija ṣi ma dun
K'Ọlọhun ma jẹ a mọya
K'Ọlọhun ma jẹ a jẹba lọ school
Ọmọ better Naija ṣi ma dun
[Chorus]
Oversability wan kill me
Versatility wan wound me
Balienciaga lẹsẹ mi
Richard Mille lọwọ mi
Mo ti mọ pe Naija ṣi ma dun
K'Ọlọhun ma jẹ a mọya
K'Ọlọhun ma jẹ a jẹba lọ school
Ọmọ better Naija ṣi ma dun
Written by: BhadBoi OML


