album cover
Skeleton
album cover
00:00
00:05
00:20
00:45
00:50
00:55
01:05
01:15
01:20
01:25
01:30
01:35
01:40
01:55
02:00
02:15
00:00
02:24
지난 7일
Skeleton은(는) 지난 주에 처음 몇 초 동안에 가장 많이 검색된 곡입니다.

가사

[Intro]
Ah ha eh eh eh e
Ah ha eh eh eh e
Femi Vega lo n ṣere, ṣere
'Bilẹ
Kapaichumarimarichupako
[Verse 1]
Ole lo bọmọ jẹ
Bawo lo ṣe ma jẹ?
Emi ti n gbawo ọpẹ
Fagbo sori ninu ọyẹ
Mi o like I don’t care
You think that I care
Instead, go hard, ẹnu o ra private jet
[PreChorus]
One million advisers no money
Can’t take you serious I’m sorry
Wọn polowo ọja d'ọdọ mi
Can’t take you serious I’m sorry
[Chorus]
I get skeleton in cupboard o
Owo apekanuko
O surplus o
Ọmọ igboro n wa mi o
I get skeleton in cupboard o
Owo apekanuko
O surplus o
Ọmọ igboro n wa mi o
[Verse 2]
Awon were wonda wonda
Bi mo ṣe pada dẹni to wa n lavish
Iranlọwọ kekere la beere fun lọjọsi
T'ọn boju wa jẹ sẹ t'ọn laali
Sardine melo lo fẹ yo mi?
Ẹgbọn adugbo ẹ kọ mi b'ọn ṣe n pẹja
Ẹ ma jẹ ki n fi were jọja
Ẹ ma jẹ ki baba atọmọ pada suffer
Ah, ori ade o ki n rupo
Now even afọju e dey see as e dey go
More money less stress, 24/7 ita la wa, 100 meter for a show
Them say skeleton go dey the cupboard with the way I dey denge po
Ta lo gbin, ta lo kun, ta lo fẹ complain ti Tinubu ba yaso?
[PreChorus]
One million advisers no money
Can’t take you serious I’m sorry
Wọn polowo ọja d'ọdọ mi
Can’t take you serious I’m sorry
[Chorus]
I get skeleton in cupboard o
Owo apekanuko
O surplus o
Ọmọ igboro n wa mi o
I get skeleton in cupboard o
Owo apekanuko
O surplus o
Ọmọ igboro n wa mi o
Written by: Ogundayomi Oluwafemi Olawale, Omoniyi Temidayo Raphael
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...