album cover

FOCUS

114African2026
album cover
FOCUS은(는) {albumName} 앨범에 수록된 곡으로 2026년 7월 31일일에 Gwarzo Diamond Music에서 발매되었습니다.FOCUS - Single
발매일2026년 7월 31일
라벨Gwarzo Diamond Music
BPM95
멜로디에 강한 음악
어쿠스틱 악기 중심
발랑스
춤추기 좋은 음악
에너지

가사

[Intro]
Ehn, Idowest awa mafia in the building, 60 by 120
About 465 inches, ẹ lọ lo fi n wa pa, owo ni o pa, eeyan ijawuta, ahh
Say Nagaxa uno, say Nagaxa unoo
[Verse 1]
Lost a lot of friends
Lost a lot of girls
But I never lost focus
I never lost focus
Fumbled with my ex
Fumbled with the next
But still a **** focus
I never lost focus
I no really send
E dey gba for my head
For the ghetto dema know us
Giovani Van Bronckhorst
[Chorus]
K'ẹni, k'ẹni no whine us
Ki lo ni, tẹ, t'ẹnikan o ra jọ?
Steady plussing and minus
Ọgbẹni, 'gbẹni ma lọ waja oh
K'ẹni, k'ẹni no whine us
Ki lo ni, tẹ, t'ẹnikan o ra jọ?
Jẹjẹly mo n fire down
Ọgbẹni, 'gbẹni ma lọ waja oh
[Verse 2]
Emi ẹṣinkẹṣin, kẹ lọ beere mi
Wọn ni Idowu o n tẹwo ọmọ were ni
Gbogbo bi n ṣe n daṣẹ ni Baba n f'ere si
Gaxa ma gba gas, ma gba fere si
Jẹ n gbadun lo ma gbadun, ma lọ dọmọpọ ni Massey
Nigba yẹn t'ẹnu gbẹ, mo pop molly mi o tun happy
Bukky dẹ ti break up oju mi bo ko si barney
Bi n ṣe n f'arizona waso, ijahuta o lowo cali
Overconfidence lo n worry mi, mi o le lose faith
But mo ti faṣẹ, faṣẹ loose weight
Mo ti n gbawẹ, gbawẹ lati two days
Mi o fẹ fall bi naira o ti lose rate
[Verse 3]
As a youngy from Lagos
Say we no dey trust favours
Steady pressing calculators
They only care about the status
[Verse 4]
Lost a lot of friends
Lost a lot of girls
But I never lost focus
I never lost focus
Fumbled with my ex
Fumbled with the next
But still a **** focus
I never lost focus
I no really send
E dey gba for my head
And to find yawa no cost
[Chorus]
K'ẹni, k'ẹni no whine us
Ki lo ni, tẹ, t'ẹnikan o ra jọ?
Steady plussing and minus
Ọgbẹni, 'gbẹni ma lọ waja oh
K'ẹni, k'ẹni no whine us
Ki lo ni, tẹ, t'ẹnikan o ra jọ?
Jẹjẹly mo n fire down
Ọgbẹni, 'gbẹni ma lọ waja oh
[Chorus]
K'ẹni k'ẹni no whine us
Ki lo ni, tẹ, t'ẹnikan o ra jọ?
Steady plussing and minus
Ọgbẹni, 'gbẹni ma lọ waja oh
Jẹjẹly mo n fire down
Ọgbẹni, 'gbẹni ma lọ waja oh
Written by: Jimoh idowu wasiu, Nuradeen Ismaila

Shazam 꼬리말

언어 선택:
Google Play Store
Apple App Store
Chrome Web Store
Galaxy Store

Shazam 팔로우하기

Loading...