album cover
X2
album cover
X2은(는) {albumName} 앨범에 수록된 곡으로 2026년 9월 1일일에 Leehard에서 발매되었습니다.GLOBAL AURA
Released2026년 9월 1일
라벨Leehard
언어English
BPM114
멜로디에 강한 음악
어쿠스틱 악기 중심
발랑스
춤추기 좋은 음악
에너지

가사

Body wey sweet , body wey sweet like pito
Show dem your level, jẹ́ kó mọ̀ pé olè tó"
I get plenty money , mo ni ma lọ̀ fi mi leko
Isale yẹn gan gan de lo ṣe kókó
Mo máa jaye x2
Gbe ọ́mọ́ to ni tattoo
lose my sense for you
Double the price over 2
Mo máa jaye x2
Gbe ọ́mọ́ to ni tattoo
lose my sense for you
Double the price over 2
A winner is a dreamer , Eyan Nelson Mandela.
Wizzy nah machala, Eruku yápà won ti n ba
Ládugbó mi, wọ́n rán èyàn, gé ori kò tún gé apá.
Awon ọ́mọ́ mi jaye dubai , awon ọ́mọ́ mi won para
Melo melo melo melo ọ́mọ́ ti mo do melo ?
Kilo kilo kilo kilo ọ́mọ́ ti mo gbe kilo
Ṣe o wà bayìí?
ọmọ ti mo gbe lọ đun bayi
Body wey sweet like Ọpẹ́yìn
Fún mi je mo ni la dę yin
Uhh uhh
Ṣe o wà bayìí?
ọmọ ti mo gbe lọ đun bayi
Body wey sweet like Ọpẹ́yìn
Fún mi je ko ya la dę yin
Mo máa jaye x2
Gbe ọ́mọ́ to ni tattoo
lose my sense for you
Double the price over 2
Mo máa jaye x2
Gbe ọ́mọ́ to ni tattoo
lose my sense for you
Double the price over 2
Oohhhh
Written by: Temitope Nurudeen Liadi
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...