album cover
Adua
album cover
Adua은(는) {albumName} 앨범에 수록된 곡으로 2021년 5월 24일일에 Oriyomi Media Planet에서 발매되었습니다.Idera
앨범Idera
2021년 5월 24일
라벨Oriyomi Media Planet
언어English
BPM125
멜로디에 강한 음악
어쿠스틱 악기 중심
발랑스
춤추기 좋은 음악
에너지

뮤직 비디오

뮤직 비디오

가사

Eda ema f'adua sile o
Kale debi a felo
Awon tonse adua
Won ma ti d'asegun
Ao debi aunre o
Aye ope ayoo
Ema je ka f'adua sile o
Kale debi a felo
Awon tonse adua
Won ma ti d'asegun
Ao debi aunre o
Aye ope ayoo
Aye eni banse adua, kole le koko
Agbe ton fun irungbin semope, tiko ba f'omi si
K'ere oko ma padawa ku, o gbodo f'omisi
Lafiwe ka sadua o, eni toba roju, tonji loru ton sadua o, kole se lasan
Adehun Olohun ud-unny, astajbulakum
Olohun ni e pemi o
Nwo si ma je logan
Kama f'adua sile o
Kale debi a felo
Awon tonse adua
Won ma ti d'asegun
Ao debi aunre o
Aye ope ayoo
Kosi bi motor sele tuntun to, taoba f'epo si
Kosibi ti oko nre o, katete ropo si
Bi epo motor l'adua o, pataki loje
Eda nsise onlàágùn, kowa ranti pe, adua longba agbara ko o, afi karoju
Se irawo loni ebun loni o? Kole sha'na to
Bi keniyan o ma sadua o, kole tan ina kari, eni nro p'adua kiigba o, koseto rara
Danwo lobi iya okere o, oma r'ope da
Kama f'adua sile o
Kale debi a felo
Awon tonse adua
Won ma ti d'asegun
Ao debi aunre o
Aye ope ayoo
Osese k'adua ma gba, bao nise lowo, ema shimi gbo eni o riseko o, òlé nimowi
Ko f'igi sáàrò o wa nbere, ogunna nko
Ole nsadua kosise o, ofo lo gbamu, koma seni towa nipo, koma sise rara
Afi eniyan tio ba dape o, bi arun opolo
Ma wa nile kowa ma reti, eni ma gbowo wa
Mase imele wona atije o, kosi ma ranti pe
Kama f'adua sile o
Kale debi a felo
Awon tonse adua
Won ma ti d'asegun
Ao debi aunre o
Aye ope ayoo
Muhammadu mi soro seyin o, kafi rogbon ko, kullu duai mustajabun, l'oro onisenla
Sawa-an fi duniya, awwil aakhira
Kosadua ti eyan ba ngba o, tio ni ropeda, b'eniyan bawa nsadua, koye sowipe
Tio bafi to osu tonbo, oye kin rile ko
Tio ba je nigba to nro, o le ronu wipe, oun o ro p'adua yen gba o, ero gidi ko
Ka s'adua bi eni fise, esin nikan ni, eyi tose soke pelu eyi, tose ni jeje
Gbogbo e ni ya robbi mase o, nigba toba to, iwo ma fadua sile o
Kale debi a felo
Awon tonse adua
Won ma ti d'asegun
Ao debi aunre o
Aye ope ayoo
Oni faari lori adua o, iyen tunwa nko, bo nkirun a kejika ru, a s'apa kanda
Bo kirun tan kosadua, af'ijoko ako
Koni ka ese ko kojoko tan o, bi eni to j'eru, ijoko eni nse faaji nijoko tonjo
Ogbagbe tolo b'olowo, lona ati toro, wakati kan koi r'olowo, igba t'olowo de
Boseyo loti dobale o, igba to r'olowo, ogbon iseju lofi dobale o, feniyan lasan ooooo
Owa nbelohun adua o, ofi igara si
Wa tunma gbe call lori e, oisetan rara, eje ka f'olohun laponle o
Kale debi a felo
Awon tonse adua
Won ma ti d'asegun
Ao debi aunre o
Aye ope ayoo
Oloroju nibi adua o, eni to kewu, ope nakali adua o, malo ni lori
Tobawa nsadua lowo o, kowa ni fe pe
Bo nkirun ama kanju, adalu lonki
Sewa reni tonsadua, lai kewu rara, awon ona t'adua fingba, sebiwo lo ko
Sungbon toripe o f'aye sile, fun akosori, kotun f'olohun e sile, nigba gbogbo ni
Toru tosan o nsadua o, niofi se lasan, emaje ka f'adua sile o
Kale debi a felo
Awon tonse adua
Won ma ti d'asegun
Ao debi aunre o
Aye ope ayoo
Allah lailaha illa llah, Allah lailaha illa llah
Allah lailaha illa llah, Allah lailaha illa llah
Allah lailaaaaaaaaaa
Allah lailaha illa llah, Allah
Allah lailaha illa llah
Duauna mustajabun
Allah lailaha illa llah
Yah robbi antal mujiibun, Allah lailaha illa llah
Wa anta robbil haseebun, Allah lailaha illa llah
Faltuf bina kulla hiinin, Allah lailaha illa llah
Wa naj-jina min uyunin, Allah lailaha illa llah
Yesirlanaaaaaaa
Allah lailaha illa llah
Yesirlana li aysha robbiy, Allah lailaha illa llah
Fa-anta nasri wa hasbiy, Allah lailaha illa llah
Wakun kariimaaaaaaa. Allah lailaha illa llah
Wakun karima mu-inan, Allah lailaha illa llah
Minnal balaya asiinan, Allah lailaha illa llah
Duaunaaaaaa, Allah lailaha illa llah
Duauna mustajabun, Allah lailaha illa llah
Duauna mustajabun, Allah lailaha illa llah
Written by: Oriyomi Kehinde Sanni
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...