Credits

COMPOSITION & LYRICS
Chisom Ezeh
Chisom Ezeh
Songwriter
Teniola Apala
Teniola Apala
Songwriter
Omoniyi Temidayo
Omoniyi Temidayo
Songwriter
Azeez Fashola
Azeez Fashola
Songwriter

Songteksten

(Rexxie 'pon this one)
Ti maga ẹ ba san owo
Ṣo ma fi Hennessey fọ'yin? (Ṣo ma fi Hennessey fọ'yin) eh-eh
T'owo yẹn ba lọ pọ (t'owo yẹn ba lọ pọ)
Alaye mi, ṣo ma f'owo nu'di? (Ṣo ma f'owo nu'di?)
Naira Marley, igbo labi (igbo labi)
Ìyẹn o ma n figbo fọ'yin (o ma n figbo fọ'yin)
Teni Makanaki, orin labi
Ay-ay, o ma n f'orin fọ'yin (jẹ ọ mọ)
Aye o pe meji o, yeah
Ẹni lowo ma lo n gb'ọmọ meji (lo n gb'ọmọ meji)
Ma lo n gb'ọmọ meji (lo n gb'ọmọ meji)
Ẹ jijo bali, gbe body o (gbe body, ye)
So, live your life, no send nobody, yea-yea
No send nobody, yea, yea
Huh-huh, kuro nbẹ
Awọn ọmọ mi Peckham
Wọn ni curve biti David Peckham, ay-ay
Awọn ọmọ Manchester to n ba ti enter
Everywhere o ma n scatter, kuro nbẹ
Awọn ọmọ mi n Dublin, kini aya wọn biti tangerine
Gbe si mi lẹnu, gbe si mi lẹnu
Owo wa nilẹ, jọọ, ko dẹ si ìyọnu (o ya)
Jesu, come and take control, ay-ay, so I can control my, flesh
Mo dẹ fẹ jaiye gan-an, o ṣa mọ, I can't come and kill myself
Jesu, come and take control, ay-ay, so I can control my, flesh
Mo dẹ fẹ jaiye gan-an, o ṣa mọ, I can't come and kill myself (kuro nbẹ)
Ti maga ẹ ba san owo
Ṣo ma fi Hennessey fọ'yin? (Ṣo ma fi Hennessey fọ'yin) eh-eh
T'owo yẹn ba lọ pọ (t'owo yẹn ba lọ pọ)
Alaye mi, ṣo ma f'owo nu'di? (Ṣo ma f'owo nu'di?)
Naira Marley o, igbo labi (igbo labi)
Ìyẹn o ma n figbo fọ'yin (o ma n figbo fọ'yin)
Teni Makanaki, orin labi
Ay-ay, o ma n f'orin fọ'yin (jẹ ọ mọ)
Aye o pe meji o, yeah
Ẹni lowo ma lo n gb'ọmọ meji (lo n gb'ọmọ meji)
Ma lo n gb'ọmọ meji (lo n gb'ọmọ meji)
Ẹ jijo bali, gbe body o (gbe body, ye)
So, live your life, no send nobody, yea-yea
No send nobody, yea, yea
I wan use palm clean my yarnsh
Ace of spade to wash my mount (ace of spade to wash my mount)
Make money, money, make money, money all day
Me, I cannot come and die
Ṣe mi Naira Marley (Ṣe mi Naira Marley)
Igbo labi (igbo labi)
Figbo fọyin, ko dẹ ni da fun iyalaya yin
Igbo labi ti Kuti
Big spliff like Marley (ay-ay)
Bad girl like Riri
Are beautiful? Are you sexy? (Are you sexy?)
Eyan Tiwa Savage
I'm from UK, 21 Savage
You wan allow sausage?
Baby, come get your punpun damaged (kuro nbẹ)
Ti maga ẹ ba san owo
Ṣo ma fi Hennessey fọ'yin? (Ṣo ma fi Hennessey fọ'yin) eh-eh
T'owo yẹn ba lọ pọ (t'owo yẹn ba lọ pọ)
Alaye mi, ṣo ma f'owo nu'di? (Ṣo ma f'owo nu'di?)
Naira Marley, igbo labi (igbo labi)
Ìyẹn o ma n figbo fọ'yin (o ma n figbo fọ'yin)
Teni Makanaki, orin labi
Ay-ay, o ma n f'orin fọ'yin (jẹ ọ mọ)
Aye o pe meji o, yeah
Ẹni lowo ma lo n gb'ọmọ meji (lo n gb'ọmọ meji)
Ma lo n gb'ọmọ meji (lo n gb'ọmọ meji)
Ẹ jijo bali, gbe body o (gbe body, ye)
So, live your life, no send nobody, yea-yea
No send nobody, yea, yea
Ti maga ẹ ba san owo
Ṣo ma fi Hennessey fọ'yin? (Ṣo ma fi Hennessey fọ'yin) eh-eh
T'owo yẹn ba lọ pọ (t'owo yẹn ba lọ pọ)
Alaye mi, ṣo ma f'owo nu'di? (Ṣo ma f'owo nu'di?)
Naira Marley o, igbo labi (igbo labi)
Ìyẹn o ma n figbo fọ'yin (o ma n figbo fọ'yin)
Teni Makanaki, orin labi
Ay-ay, o ma n f'orin fọ'yin (jẹ ọ mọ)
Aye o pe meji o, yeah
Ẹni lowo ma lo n gb'ọmọ meji (lo n gb'ọmọ meji)
Ma lo n gb'ọmọ meji (lo n gb'ọmọ meji)
Ẹ jijo bali, gbe body o (gbe body, ye)
So, live your life, no send nobody, yea-yea
No send nobody, yea, yea
(Yo Rexxie 'pon this one)
(Spyrit Mix)
Written by: Azeez Fashola, Chisom Ezeh, Omoniyi Temidayo, Omoniyi Temidayo Raphael, Teniola Apala
instagramSharePathic_arrow_out

Loading...