Muziekvideo

Ayanfe
Bekijk de videoclip voor {trackName} van {artistName}

Credits

PERFORMING ARTISTS
Teledalase Ayomide Ogundipe
Teledalase Ayomide Ogundipe
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Teledalase Ayomide Ogundipe
Teledalase Ayomide Ogundipe
Songwriter

Songteksten

Mo ni ife re nitooto N 'o puro N'o puro oo Mo mo ogbe Okan re nitooto Amo emi yato oo N 'o puro N o gbe o rin do Ese re oni kan 'mi N o ba o roke Ese re oni kan le Mo shey ogbingbin Je n ba o lo Ibi o ba nnlo N 'o ba o re N 'o ba o re Ayanfe, je n ba o rele oo Ibi o ba nlo N o ba o lo N o ba o lo Won ni ki layanmo mi Mo ni Iwo ni Won ni ki layanmo mi Ife re ni Irin wa ti di ajorin Ebo wa ti di ajogbe N o puro oooo N o puro ooo N o gbe o rin do Ese re oni kan mi N o ba o ro ke Ese re oni kan le Ayanfe Jen ba o dele Ibi o ba nnlo Ibi o ba nnlo Ayanfe Jen ba o dele Ibi o ba nlo oo N o ba o lo ooo Ila lomo oriki ila oooo Ogiri lomo oriki ooobe ooo Ayanfe dakun dabo shey temi Ibi o ba nnnlooo ooo Ayanfe, Ayanfe ee mi Ayanfe je n ba o dele oo Ibi o ba nnlooo Ibi o ba nnlo oo Ayanfe dakun shey temi Irin wa ajorin Ebo wa ajogbe Iku wa ajoku (Keyboard sounds)
Writer(s): Teledalase Ayomide Ogundipe Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out