Muziekvideo

Muziekvideo

Credits

PERFORMING ARTISTS
Barry Jhay
Barry Jhay
Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Oluwakayode Balogun
Oluwakayode Balogun
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Dibstunez
Dibstunez
Producer

Songteksten

[Intro]
Ẹ maa ka mi mọ wọn, ṣe ni mo da duro
Ọrọ mi dakọ alangba, ko ṣe jẹ ni tutu
Koda, ko ṣe China t'ọn gbe ti n jẹ wọn
Ẹni jalangba n tutu, a ko warapa
[Intro]
Oh-ah, oh-ah-ah-ah
Yeah, ay-ya-ay, ah-ah, ah
Oh-wa, oh, wa-wa-wa
(Nobody's perfect)
[Verse 1]
Yea, ki iku ma ma pa awọn to gbe mi sori bi gele
Ki ibaunjẹ jina si wa rere, ay, tefetefe
Ki iku ma pọta mi, ko le riranwo
O ri mo fa to n jo, and they no fit hold me, different effect, ah
Ki iku ma pọta mi, ko le riranwo
Mo ṣi n mẹyẹ bọ lapo, a jẹ gbese LAPO, ọta mi lo n jẹ gbese, mo mọwọ na
[Verse 2]
If I see say wahala don dey too much
Na to roll up a big fat one
Motivation gan-an ti n payan, wahala nikan kọ o
Ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko mi yọ ọ
(Ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko mi yọ ọ)
[Chorus]
See me, see God o, abi emi naa kọ?
Ọmọde ana ti wèrè bọ, gentle boy, yeah-yeah
Ṣe you dey see level o?
Barry lo n bọ, ọmọ ọba lo n bọ, oh yeah, tẹti mọ ọ (Yeah)
[Verse 3]
Yeah, as I dey find wetin I go chop, ooh-iy-iy
Make I no jam wetin go chop me
Oluwa lo gbe (Yea-yea), lo gbe mi soke
Emi ko le ṣai ṣọpẹ
[Chorus]
See me, see God o, abi emi naa kọ
Ọmọde ana ti wèrè bọ, gentle boy, yeah-yeah
Ṣe you dey see level o? (Ṣe you dey see level o?)
Barry lo n bọ, ọmọ ọba lo n bọ, oh yeah, tẹti mọ ọ (Yeah)
[Verse 4]
Yeah, o loju ọmọ to damọ
If I see say wahala don dey too much
Na to roll up a big fat one
Motivation gan-an ti n payan, wahala nikan kọ o
Ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko mi yọ ọ
(Ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko mi yọ ọ)
[Chorus]
See me, see God o, abi emi naa kọ
Ọmọde ana ti wèrè bọ, gentle boy, yeah-yeah
Ṣe you dey see level o? (Ṣe you dey see level o?)
Barry lo n bọ, ọmọ ọba lo n bọ, oh yeah, tẹti mọ ọ (Yeah)
Yeah, o loju ọmọ to damọ
[Outro]
(Sunshine)
Written by: Oluwakayode Junior Balogun
instagramSharePathic_arrow_out

Loading...