Tekst Utworu

Wan ran 'mọ lọ'ja Ko lo r'ori ọkà oni nọyin wa Wan ran 'mọ lọ'ja Ko lo r'ori ọkà oni nọyin wa Itun meje, at'arẹ meje pẹlu adere meje Wan wa gun pọ, wan ko m'ọṣẹ dudu Wan wa gbefun padi ẹ Padi Ọdẹnson Wan wa gbefun padi ẹ (Padi Ọdẹnson) Wan wa gbefun padi ẹ (Padi Ọdẹnson) Oṣika ma ṣe'ka mọ o (Ika a p'oni'ka o) Oṣika ma ṣe'ka mọ o (Ika a p'oni'ka o) Oṣika ma ṣe'ka mọ o (Ika a p'oni'ka o) Oṣika ma ṣe'ka mọ o (Ika a p'oni'ka o) Ika a p'oni'ka o (Ika a p'oni'ka o) Ika a p'oni'ka o (Rere a b'ẹni rere) Ika a p'oni'ka o (hee) (Rere a b'ẹni rere) Odaju Ẹni gbẹkun gba laye Aya rẹ a jẹ, ọmọ rẹ a jẹ Oun naa a wẹwẹ sẹ
Writer(s): Sunny Ade Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out