Tekst Utworu

Iyin yeah o Oba to femi Ogo ye o Oba to femi Kabiesi re o Iyin ye o Oba to femi Ogo ye o Kabiesi re o eh Ogba mi lowo iku Ore mi otito Ofi keke ogun aye mi jona Olu gbe ja mi ni Ko se ni to le se o; afi wo Kabiesi re o eh Mo juba mo fori ba le fo ba Iwo ni ologo julo O fo gbogbo ilekun ide aba wole si ogo mi Ojo gbogbo jankari wo Emi odi won teriba Okuta ti awon mole ko Wadi pataki igun aye Owo anu re to fi gba mi oga Mose ba fele yinju ife Ona mi la mo ri ore ofe La to do Aseda Owo olonde ge so nu Ohun ija won lo nu loro Emi leri emi lo go Asotele ni mo je Majemu Olorun fohun la ye mi Mo fiyin fa duro ti ni gbangba Emi leni ti Oluwa fe gan Ti ati da lare
Writer(s): Patricia Temitope Alabi Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out