album cover
Italia
82 447
Hip-Hop/Rap
Utwór Italia został wydany 29 listopada 2023 przez Ziiki Media jako część albumu Dessigna + Italia - Single
album cover
Najpopularniejszy
Ostatnie 7 dni
01:10 - 01:15
Italia był najczęściej odkrywanym utworem w czasie około 1 minuty and 10 sekundy do w ciągu ostatniego tygodnia
00:00
00:15
00:20
00:40
00:45
01:00
01:10
01:45
00:00
02:18

Teledysk

Teledysk

Tekst Utworu

[Intro]
Ehmu
Pawo ma payan
Focus
Ẹmi mi
Ẹkun ni ayiri
[Chorus]
Iba Gaza ma fi ozo pill up ninu giri
Jiggy baller mo fi n boju fawọn ti ko ri mi
Amiri toke tilẹ, ẹku bi ayiri
Gbe awọn rapper l'handicap k'ọn to pari season
Ogini gini baki ninu Lamboghini
Ẹri mo fi jini ẹ ẹ le wa ma fun mi n ṣiri
Bo wu mi ma la merili
Ologo billi billi
Cartier ni mo ji ri
Emi Idowu girigiri (Emi Idowu girigiri)
[Verse 1]
Amigo casamigo
Lagi kaba C and 7 lori camo
Shoe gbẹngbẹ mo wọ sẹsẹ bata Jago
Wọn lo n fowo LAPO gara bi ẹni n gbowo ato
Wọn ni mo ni shooter ninu office agba picker
Ko to gbowo japa mo le P'Eṣo, Baba Ruka
Baba Amuda wako ọmọ aye ko gọ bi hoofer
Ma fi aita yanna, German machine, Kwame Nkruma
Talo le gbowo yẹn, o wo bata ẹ lori Gucci
Para wa n'lẹ fun awọn rapper to n wọ hoodie (Awọn rapper to n wọ hoodie)
Democracy wa di huzzi
Yahoo takalada melo lori huppy
Jesu ọmọ Mary, ma ṣepese lọjọ Jimọh
Tori mo mu ṣẹpẹ mo da coco sinu liquor
Lọdọ Mummy Shina mo ti mu ọja fọ wọn n mirror
Onile orita tun ti ṣile sinu Pinnock
[Chorus]
Iba Gaza ma fi ozo pill up ninu giri
Jiggy baller mo fi n boju fawọn ti ko ri mi
Amiri toke tilẹ, ẹku bi ayiri
Gbe awọn rapper l'handicap k'ọn to pari season
Ogini gini baki ninu Lamboghini
Ẹri mo fi jini ẹ ẹ le wa ma fun mi n ṣiri
Bo wu mi ma la merili
Ologo billi billi
Cartier ni mo ji ri
Emi Idowu girigiri (Emi Idowu girigiri)
Written by: Jimoh idowu wasiu
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...