album cover
Store
album cover
Utwór Store został wydany 27 lutego 2024 przez 3712891 Records DK jako część albumu Store - Single
Released27 lutego 2024
Wytwórnia3712891 Records DK
JęzykEnglish
BPM97
Melodyjność
Akustyczność
Valence
Taneczność
Energia

Tekst Utworu

Whoa-whoa-whoa
Yeah, yeah, yeah, ah
Brokenness is my greatest fear (Godspower on the beat)
Omo'pé, oni láti san sokoto ẹ giri
Ko bá le gba gíri
Ile ayé yìí kògba'gidi
Sùlẹ' tí ṣe yahoo fún ọdún mẹ'ta, ko gba sìsì
Tí ó bá sì owó lọ'wọ', mo má n sober
Má pè Yinka kò yá mi lọ'wọ'
Àpò mi tí là bí taya móto
Tí n bá ra móto o, sey na auto o
I don too taya for borrow, borrow
Atewó mẹ'ta, mẹ'ta
Pastor de tí mú Seaman mẹ'ta
Àwọn kan gbè'bo s'oríta
Boys dem dey para with Barreta
Àwọn kan dém w'óṣe àwó'ro o, kò lè rè'rò
Ohùn t'érì kò lè l'éro o
Something dey inside there
I'm a sharp boy, kí n má sùn lé
Láti kékeré mìó kí n sùn lé
Eni bá sùn ní kò ní sùn
'Tòri pé èmí fé rà'lé o
I'm a sharp boy, kí n má sùn lé
Láti kékeré mìó kí n sùn lé
Eni bá sùn ní kò ní sùn
'Tòri pé èmí fé rà'lé o
My client is on the way to store
Ó fé ló dà'wo
He's just five miles to the store
Ó fé ló s'owó mi (ó fé ló s'owó mi)
My seven years client no dey dull me
Picker mi bàmí gb'ówó mi, bàmí gb'ówó mi
Tí n bá ra móto o, sey na auto o
I don too taya for borrow, borrow
Atewó mẹ'ta mẹ'ta
Pastor de tí mú Seaman mẹ'ta
Àwọn kan gbè'bo s'oríta
Boys dem dey para with Barreta
Àwọn kan dém w'óṣe àwó'ro o, kò lè rè'rò
Ohùn t'érì kò lè l'éro o
Something dey inside there
I'm a sharp boy, kí n má sùn lé
Láti kékeré mìó kí n sùn lé
Eni bá sùn ní kò ní sùn
'Tòri pé èmí fé rà'lé o
I'm a sharp boy, kí n má sùn lé
Láti kékeré mìó kí n sùn lé
Eni bá sùn ní kò ní sùn
'Tòri pé èmí fé rà'lé o
My client is on the way to store
Ó fé ló dà'wo
He's just five miles to the store
Ó fé ló s'owó mi
My seven years client no dey dull me
Picker mi bàmí gb'ówó mi, bàmí gb'ówó mi
Major!
Skète bàmí pass lighter yẹn, bàwo ló ṣe ń ṣe báyìí
Written by: Oluwadamilola Adeniyi Adewole
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...