album cover
Sha Guide
9641
Music
Utwór Sha Guide został wydany 2 marca 2026 przez Zeh Nation jako część albumu Sha Guide - Single
album cover
Najpopularniejszy
Ostatnie 7 dni
00:00 - 00:05
Sha Guide był najczęściej odkrywanym utworem w czasie w pierwszych kilku sekundach w ciągu ostatniego tygodnia
00:00
00:10
00:20
00:30
00:40
00:45
01:05
01:15
01:35
01:50
02:10
00:00
02:25

Teledysk

Teledysk

Kredyty

PERFORMING ARTISTS
Portable
Portable
Performer
Akanbi Hassan
Akanbi Hassan
Drums
COMPOSITION & LYRICS
Habeeb Okikiola
Habeeb Okikiola
Composer
PRODUCTION & ENGINEERING
Akanbi Hassan
Akanbi Hassan
Producer

Tekst Utworu

[Intro]
Tuti on the beat
Ọmọ Ọlalọmi again o, they call me Portable baby (Popo when)
[Chorus]
‎Ija wa ija o si (Ṣa guide)
‎Da ti ẹ mọ (Ṣa guide)
‎Eeyan wa eeyan o si (Ṣa guide)
‎E get why (Ṣa guide)
‎Sabo plus Oluwore (Ṣa guide)
‎Wọn a ṣẹke sinu idi ẹ (Ṣa guide)
‎Wọn a fẹnu gba pata n'di ẹ (Ṣa guide)
‎Elo lo wa l'account ẹ? (Ṣa guide)
‎Ha, ogun laye (Ṣa guide)
‎Logun awure, ṣogun ayẹta (Ṣa guide)
‎If you price you go pay (Ṣa guide)
‎Olowo l'ọn pe lalaye (Ṣa guide)
[Verse 1]
‎Ọmọ dudu, ọmọ pupa
‎Gbogbo wọn ni mo ti pa
‎Elo ni price ẹ?
‎Mo ma fi universe gba pata n'di ẹ
‎Mo ma fún ẹ ni lion
‎To gbe money gun dani (Ṣa guide)
‎Mufasa mufasa (Ṣa guide)
‎Lion ẹkun mẹfa (Ṣa guide)
‎Talo fa ẹ laṣọ ya?
‎Sunmọ ẹni ti iwọ ba ja
Ọgbẹni gbori ẹ sa nibi t'ọn ti n yin ṣakabula
[Chorus]
‎Ija wa ija o si (Ṣa guide)
‎Da ti ẹ mọ (Ṣa guide)
‎Eeyan wa eeyan o si (Ṣa guide)
‎E get why (Ṣa guide)
‎Sabo plus Oluwore (Ṣa guide)
‎Wọn a ṣẹke sinu idi ẹ (Ṣa guide)
‎Wọn a fẹnu gba pata n'di ẹ (Ṣa guide)
‎Elo lo wa l'account ẹ? (Ṣa guide)
‎Ha, ogun laye (Ṣa guide)
‎Logun awure, ṣogun ayẹta (Ṣa guide)
‎If you price you go pay (Ṣa guide)
‎Olowo l'ọn pe lalaye (Ṣa guide)
[Verse 2]
‎Ọmọ ki lo fi ṣe ibadi? O ya ligali
‎Ṣe Southy lo ti ṣebadi?
‎Nobody is calling me
‎O ya liga ligali mo tun ti de
‎Ohun to ba wu wọn ni k'ọn sọ
‎Liga ligali awa tun ti de o
‎T'owo ba de gọngọ a sọ
‎Money gun mẹfa fun eeyan kan
‎Baby lion mẹta fun ẹnikan
‎Ẹ fun lọrun pa
Ẹ yi loruka
[Chorus]
‎Ija wa ija o si (Ṣa guide)
‎Da ti ẹ mọ (Ṣa guide)
‎Eeyan wa eeyan o si (Ṣa guide)
‎E get why (Ṣa guide)
‎Sabo plus Oluwore (Ṣa guide)
‎Wọn a ṣẹke sinu idi ẹ (Ṣa guide)
‎Wọn a fẹnu gba pata n'di ẹ (Ṣa guide)
‎Elo lo wa l'account ẹ? (Ṣa guide)
‎Ha, ogun laye (Ṣa guide)
‎Logun awure, ṣogun ayẹta (Ṣa guide)
‎If you price you go pay (Ṣa guide)
‎Olowo l'ọn pe lalaye (Ṣa guide)
[Outro]
Tuti on the mix
Written by: Habeeb Okikiola
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...