album cover
Never Fold
album cover
Utwór Never Fold został wydany 29 października 2026 przez Chabalaja / EMPIRE jako część albumu MERAKI - EP
29 października 2026
JęzykEnglish
BPM101
Melodyjność
Akustyczność
Valence
Taneczność
Energia

Teledysk

Teledysk

Tekst Utworu

Tune into the King of Sounds and Blues
Ẹni dúró t’Olúwa kìn jo’gún òfò
I never fold
Jalla Jalāluhu Ọba Ajọkẹ́ ayé, Àṣàkẹ́ ọ̀run
so i dey on my Yoga
Ìbílẹ̀ ni mí, ọmọ Yooba
Ẹni lọ́wọ́ ló ń ló gba
Ọmọ lọ̀gbà lọ̀gbà
Wake up for your sleep, don’t be a dumbass
This life is rolling like a compass
So many yawa wey i jump pass
The way e dey do me for body omo na me know
Kin to gba Iya Charlie o
Fìlẹ̀ fún’mọ tó sabi o
Ana watch ya
The way e dey do me for body omo na me know
Kin to gba Iya Charlie o
Fìlẹ̀ fún’mọ tó sabi o
Ana watch ya
Ìṣẹ́ Ọlọ́run àwárí mà rídi
Gratitude is a must
Na my ghetto story i’m reading
For every each line na article
Kí Ọlọ́run tó yọ mí ní agiju (back in the trenches)
But yet i’m still pushing my P
ko se fun omo to n de nappie
Mo ń tẹ̀ rà mọ́ hustle mi dede
Before stereoman sample the ekwe (ekwe)
Ẹ pè mí sọ̀rọ̀ yẹn tó bá ti jáwọ́, ká lè jó máa láwù erẹ̀bẹ̀ láwù
Jà mí tán, tó bá bá owó dé, ká jọ kọ orin ọpẹ́ high note lóló ké
Pè mí sọ̀rọ̀ yẹn tó bá ti jáwọ́, ká lè jó máa láwù erẹ̀bẹ̀ láwù
Àní ke involve mi tó bá owó dé
Ká jọ kọrin Ayo high note lóló ké
Ẹni dúró t’Olúwa kìn jo’gún òfò
 I never fold
Jalla Jalāluhu Ọba Ajọkẹ́ ayé, Àṣàkẹ́ ọ̀run
so i dey on my Yoga
Ìbílẹ̀ ni mí, ọmọ Yooba
Ẹni lọ́wọ́ ló ń ló gba
Ọmọ lọ̀gbà lọ̀gbà
Wake up for your sleep, don’t be a dumbass
This life is rolling like a compass
So many yawa wey i jump pass
The way e dey do me for body omo na me know
Kin to gba Iya Charlie o
File fun’mo to sabi o
Ana watch ya
The way e dey do me for body omo na me know
Kin to gba Iya Charlie o
Fìlẹ̀ fún’mọ tó sabi o
Ana watch ya

Loading...