Teledysk

Kredyty

PERFORMING ARTISTS
Brymo
Brymo
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Olawale Ashimi
Olawale Ashimi
Songwriter

Tekst Utworu

Ní kékeré, a má ńṣeré À mà ń f'àwọn àgbààgbà ṣeré À má ńmere Ìyá Dele, sọ fún Dele Kò ye fó 'na, kò tó wo 'na, ko to mere Bọ 'mọdé ńṣeré, kò tó ṣeré délé Àwọn àgbà-gbà wọn mà ṣé'to were-were Bọ 'mọdé ńṣíṣẹ, ko tó rí jẹ Ìtìjú ní fún àwọn àgbà-gbà to rán ní ṣẹ Jẹ lé o sinmi ooo Jẹ lé o sinmi Jẹ k'ọmọdé o kàwé Kò kẹ'kọ' jèrè Jẹ lé o sinmi ooo Jẹ lé o sinmi Àwọn àgbà-gbà múra sí ṣẹ were-were A mà ń ṣeré À mà ń sáré À mà ńṣubú, à mà ń dídé, a mà ńdele Ìyá Taye sọ fún Taye Kò yé sọrọ, kò to mọ'rọ yeke-yeke K'ọmọ o to sa ńlé Ko tó dí pé o ń sáré kírì Àwọn àgbà-gbà wọn má ṣètò were-were B'ọmọdé ń ṣíṣẹ, ah, ko to rí jẹ Ìtìjú ní fún àwọn àgbà-gbà to rán ní ṣẹ Jẹ lé o sinmi ooo Jẹ lé o sinmi Jẹ k'ọmọdé o kàwé Kò kẹ'kọ' jèrè Jẹ lé o sinmi o, o sinmi Àwọn àgbà-gbà múra sí ṣẹ were-were (were-were) Wure, wure, wure e- Jẹ lé o sinmi (jẹ lé o sinmi) Ko sinmi (ko sinmi) K'ọmọdé o kàwé (k'ọmọdé o kàwé) Kò jèrè (kò jèrè) Jẹ lé o sinmi o (jẹ lé o sinmi o) Ko sinmi (ko sinmi) Àwọn àgbà-gbà múra sí ṣẹ were-were Ko sinmi (ko sinmi) Ani, ko sinmi (ani, ko sinmi) Ko kà'we (ko kà'we) Ko jèrè (ko jèrè) Jẹ lé o sinmi o (jẹ lé o sinmi o) Ko sinmi (ko sinmi) Ko, ko sinmi, ko-ko jèrè
Writer(s): Ashimi Ibrahim Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out