Letra

[Chorus]
Aye mi b'ọla fun ọ o, Jesu
Ẹmi mi f'ogo fun ọ o, Jesu
Aye mi b'ọla fun ọ o, Jesu
Ẹmi mi fi ogo fun ọ o, Jesu
Aye mi b'ọla fun ọ o, Jesu
Ẹmi mi, o f'ogo fun ọ o, Jesu
Aye mi b'ọla fun ọ o, Jesu
Ẹmi mi f'ogo fun ọ o, Jesu
[Bridge]
Aye mi b'ọla fun ọ o, Jesu
Ẹmi mi f'ogo fun ọ o, Jesu
[Verse 1]
Ọlọrun ẹmi o
Aye mi b'ọla fun ọ, Jesu
Ẹmi mi f'ogo fun ọ o, Jesu
Ọba to ni mi, to da mi, to mọ mi o
Ọba to ni mi, to da mi, to mọ mi o, oh oh oh oh oh ah
Ọba to ni mi, to da mi, to mọ mi o
Ọba to ni mi, to da mi, to mọ mi o
Ọba to ni mi, to da mi, to mọ mi o, oh oh oh oh oh
Ọba to ni mi, to da mi, to mọ mi o, ayọ
Iwọ ni Ọba to ni mi, to da mi, to mọ mi o
Ọba to ni mi, to da mi, to mọ mi o
Ọba to ni mi, to da mi, to mọ mi o
Ọba to ni mi, to da mi, to mọ mi o
Ọba to ni mi, to da mi, to mọ mi o
Ọba to ni mi, to da mi, to mọ mi o
Written by: Efeoghene Donald Idu, Sunmisola Agbebi
instagramSharePathic_arrow_out

Loading...