Update
69 209
Music
Update foi lançado em 31 de agosto de 2017 por YBNL NATION como parte do álbum Update - Single
Mais popularesÚltimos 7 dias
02:05 - 02:10
Update foi descoberto com mais frequência por volta de 2 minutos and 5 segundos após a Canção durante a semana passada
00:00
00:20
01:45
02:05
02:50
00:00
03:19
Letra
[Intro]
Update! Update!! Update!!!
Young John, Update!
Ṣanawọle
[Chorus]
When would you marry?
This year, next year, long time, or never?
This year, next year, long time, or never?
Never ah, never ah
O ya, she say January, February, March
April, May, June
July, August, September
October, November, December
Lundi oh, Mardi oh, Mercredi, Jeudi
Vendredi, Samedi, Dimanche eh
Leave it!
[Verse 1]
Ọmọ Yoruba l'emi, mo appreciate culture mi
Anything you like, you call me
Orukọ to wun k'ọn sọ mi, ye
Awọn t'emi nigboro, wọn ni Baddo, ko s'iṣoro
Wọn ni ki n ma lọ ma soro
Be happy l'awa no sorrow
[Verse 2]
Ṣeb'owo n wọle wa ọbẹ o selẹ lọjọ Ileya
And the money I get, the money too long, Baba dey answer prayer
Kasimawo! Lorukọ Abiola, o ṣi ma gbọ t'emi
Kasimawo! Lorukọ Abiola, na English you wan chop ni?
[Verse 3]
Ẹ filẹ fun, Badd bish, I'm the baddest in the street
O ni ki n sọ English, bi mi o le sọ, mo finish
Ah, kini English, ṣo le define English? Ah, English
Emi le define English, edekede, ọrọkọrọ, t'iya mi o gbọ, ti baba o gbọ
T'ọn fi tipatipa kọ mi
Baby, ye kanra mọ mi
Edekede, ọrọkọrọ, t'iya mi o gbọ, ti baba o gbọ
T'ọn fi tipatipa kọ mi, baby ye kanra mọ mi
[Verse 4]
Ọmọ, yo'di e, ara fe san, eh ojo fe ro
I know you' feeling me awọn t'ọn hate, wọn kẹran, ah
Kupepi, eh, kupepi bambam
Kulusọ lo lo ni, ti kini yẹn fi tobi gbangba?
[Verse 5]
Ṣeb'owo n wọle wa ọbẹ o selẹ lọjọ Ileya
And the money I get, the money too long, Baba dey answer prayer
Kasimawo! Lorukọ Abiola, o ṣi ma gbọ t'emi
Kasimawo! Lorukọ Abiola, na English you wan chop ni?
[Verse 6]
Ẹ filẹ fun, Badd bish, I'm the baddest in the street
O ni ki n sọ English, bi mi o le sọ, mo finish
Ah, kini English, ṣo le define English? Ah, English
Emi le define English, edekede, ọrọkọrọ, t'iya mi o gbọ, ti baba o gbọ
T'ọn fi tipatipa kọ mi
Baby, ye kanra mọ mi
Edekede, ọrọkọrọ, t'iya mi o gbọ, ti baba o gbọ
T'ọn fi tipatipa kọ mi, baby ye kanra mọ mi
[Chorus]
When would you marry?
This year, next year, long time, or never?
This year, next year, long time, or never?
Never ah, never ah
O ya, she say January, February, March
April, May, June
July, August, September
October, November, December
Lundi oh, Mardi oh, Mercredi, Jeudi
Vendredi, Samedi, Dimanche eh
Leave it!
Written by: Olamide Ismail Micheal