album cover
Grateful
63 316
Music
Grateful foi lançado em 25 de agosto de 2014 por Naive como parte do álbum Bed of Stone
album cover
Mais populares
Últimos 7 dias
00:30 - 00:35
Grateful foi descoberto com mais frequência por volta de 30 segundos após a Canção durante a semana passada
00:00
00:05
00:15
00:30
00:50
01:10
01:15
01:30
02:20
00:00
02:45

Letra

[PreChorus]
Eera ilẹ, eera ilẹ wọn yin Baba loke
Yanrin okun, yanrin okun wọn yin Baba loke
Ẹranko ile, ẹranko igbo wọn yin Baba loke
Awọn alaini, awọn t'ọn ti ni wọn yin Baba loke
[Chorus]
Ko i ṣe igba ti nnkan ba ṣe ọ
Ko to mọ pe Baba n bẹ loke
Ko i ṣe igba ti nnkan ba ṣe ọ
Ko to mọ pe lootọ O n bẹ loke
You don't have to wait till you feel the pain
You can start right now
It's not too late
It's not too late, to be grateful
[PreChorus]
Eera ilẹ, eera ilẹ wọn yin Baba loke
Yanrin okun, yanrin okun wọn yin Baba loke
Pe mo wa laye, mo wa laaye
Gbogbo ohun ti mo ni, ma fi yi Ọ logo
Believe this world a better place, ah eh eh ih
[Chorus]
Ko i ṣe igba ti nnkan ba ṣe ọ
Ko to mọ pe Baba n bẹ loke
Ko i ṣe igba ti nnkan ba ṣe ọ
Ko to mọ pe lootọ O n bẹ loke
You don't have to wait till you feel the pain
You can start right now
It's not too late (It's not too late)
It's not too late, to be grateful
[Outro]
Wo mi, bi mo ṣe n fẹgbẹ yin Baba
Da di da di da
Da di da du
Da di da di da
Da di da du
It's not too late, yeh yeah
Written by: Bukola Elemide, Greg Beker, Michael Davey
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...